Friday, September 29, 2023

ISOYE OMO ILE IWE 💯

 ISOYE OMO ILE IWE 💯 

OPOLOPO NI KO MO PE ISOYE SE PATAKI FUN AWON OMO ILE IWE 

JU AWON OUNJE MIDINMIDIN TI WON NDI SI ERU WON LO.

OMO TI KO BA NI IYE NINU, IWE YOO MAA SU LATI KA. GBOGBO 

OHUN TI AWON OLUKO BA NKO IRU AWON AKEKO BEE, KO LE YE 

WON RARA. AWON AGBALAGBA PAAPAA NILO ISOYE. ONISOWO TI 

KO BA NI IYE NINU, ASEDANU YO MA PO NINU ORO WON.

BO BA JE AWON TO N KIRI OJA KAAKIRI NI, BI O BA GBA OWO NI ALO 

KONI RANTI GBA OWO NI ABO.


ASIRI ISOYE

E RA AGBON KAN TO BA TOBI DAADA.

TI E BA FE LOO FUN ISOYE, OWURO KUTUKUTU NI KI E FO AGBON YII 

E GBE OMI INU RE SINU ABO TABI KOOPU (CUP) KAN E DA SIBI OYIN 

OGIDI (ORIGINAL HONEY) KAN PELU RE.

E JE KI OMO TO FE LO FUN ISOYE KO GBE MU LESEKESE. TO BA JE PE 

AGBALAGBA NAA LO FE LO FUN ISOYE, E JE KO SE BEE BAKAN NAA.

ORO NIPA AGBON YEN, E LE JE TO BA WU YIN LATI JE, E LE SO AGBON 

YEN NU, TI E KO BA FEE JE. EEWO KAN TO WA NIBE NIPE, ENIYAN 

MEJI KO LE PIN AGBON TI E BA LO YEN JE. PELU ASE OLORUN, IYE ENI 

TO BA LO ISE YII YOO MA SI. KO NI GBAGBE NKAN TI WON N KO TABI TI WON BA SO NI ETI RE MO LAE LAE.

No comments:

Post a Comment

CONNECTION CLIENT SOAP GEE BOY 💯

 CONNECTION CLIENT SOAP GEE BOY 💯  Ewe Omisinmisin ti amo si eso oju Olohungbo Oojo tuntun die,ao fo Odidi eyin Ororo ibile ti o mo dada 1k...