AGBARA SUGAR FUN IBUKUN 💯
TI O BA WA NINU ARA AWON TO MA N PARIWO PE NNKAN LE KOKO
IGBA KO DERUN RARA.TI O BA JE ENI TI AWON MOLEBI TI PATI BI
ASO TO TI GBO. MO BE O MA SE FI IRONU PA ARA RE. ONI LE KORO,
SUGBON OLA NBO WA DARA NI IWE MIMO SO.
ASIRI NLA
LOO RA PAALI SUGAR ONI GUN KAN, SO EYO KOOKAN SI ORIGUN
MERIN YARA TI O N SUN. SO EYO KOOKAN SI ILE IDANA (KITCHEN)
RE, SO EYO KOOKAN SI PALO (PARLOUR) RE. PELU ASE OLORUN, AYO NI ORO RE YOO JASI.
No comments:
Post a Comment