ASIRI BIBO FUN ILE KIKO 💯
TI O BA ROWO RA ILE TI OKO RI OWO TO O MAA FI KO, ASIRI NLA
KAN TUN RE O. KO KI NSE GBOGBO ENI TI O RI OWO RA ILE LO MA
NRI OWO TI YOO FI KOO.
AIMOYE ENIYAN NI WON MA NTA ILE RE FUN ELOMIRAN, NIGBA TI
ENI TO RA ILE KO BA RI OWO TI YOO FI KO. OLORUN MA DAAMU
WA, AMIN NI KI E SE.
ENI TI O KAN LOMO, ELOMIRAN TI RA ILE LONA META, WON GBA
MOO LOWO GBEYIN NI. AWON BABA WAA NI OGBON TI WON MA N
DA SI ORO ARA WON. OGBON ATINUDA TI KO SI NI EWU NINU RARA.
ASIRI RE
AKII RI KEKERE IGBIN TI KONI ILE LORI.
ELO RA IGBIN NLA KAN, IGO OYIN OGIDI KAN, ODIDI AGBON NLA
KAN.
ADURA RE
IWO OLORUN OLODUMARE IWO LO DA IGBIN, A KII RI KEKERE IGBIN
TI KO NI ILE LORI, MO FE NI ILE LORI, EMI MI LORA ILE YI, EMI NI YOO
KO NI AGBARA IWO OLORUN ASEDA, ENIKAN KO MO BI OYIN TI MA
N SE AFARA, ENIKAN KO MO BI OMI TI SE MA N WO INU AGBON,
ADII TU NI ISE IWO OLORUN OLODUMARE
BAYI LETI MASE
E GBE KOTO, E GBE KO FE, KO SI JIN DAADAA SORI ILE YIN, IWAJU ILE
TI BIRIKILA KO NI LE FI SOBIRI WU OOGUN YI DANU NI O, E JU IGBIN
NLA (IGBIN APINNU) SI INU KOTO YEN, E FO AGBON YEN, KEE JO OMI
INU RE SI ORI IGBIN YEN, E DA OYIN IGO KAN LE LORI.
EMI___________________ OMO_____________________
BEBE LODO OLORUN, EMI MI TO RA ILE YI NAA NI KO KOO, ASIRI MI
KO BO, KI NRI OWO LATI KO ILE NLA SORI IWO ILE YI. LEYIN ADURA
YI, E DA ERUPE BO GBOGBO RE MOLE. PELU ASE OLORUN, E MA RI
OWO NLA, AWON ENIYAN YOO BO ASIRI RE LONAKONA.
ASIRI YI DARA, ISE ADURA NI O, E MA SE BERU
No comments:
Post a Comment