ASIRI BIBO PELU AGBADO π―
ADII TU NI ISE OLORUN, IHO HO NI AGBADO MA N WO INU EBE, TO
BA JADE TAN LO MA N DI ONIGBA ASO. EYOKAN TI AGBE BA GBIN,
TO BA DAGBA TAN, AIMOYE OMO LO MA N GBE SI ARA.
LILO RE
ELO RA AGBADO GBIGBE, ELO NI ERO OGI TABI KI E FI OWO LO NI
GBEREFU, BI EBA LO NI GBEREFU (POWDER) TAN, EGBE PAMO SINU
ILE, EWA IKE FUNFUN OLOMORI KAN, EDA SIBI OYIN OGIDI KAN SI,
EFI IYO ISEBE SIBI KAN SI, E MA LA NI OWURO KI E TO JEUN.
BI E BA TI LO TINU IKE YEN TAN, E TUN LE SE OMIRAN. E MA
GBAGBE, EYIN E SA MA GBA ADURA, KE MA SO PE IHOHO NI
AGBADO MA N WO INU EBE, TO BA JADE TAN, NI O MA NDI ONIGBA
ASO, OLORUN JEKI ASIRI MI BO LONI YI O.
PELU ASE OLORUN, ASIRI YIN YO MA BO
No comments:
Post a Comment