OMI KO NI OTA (WATER HAS NO ENEMY) 💯
OMI NI ABU MU, OMI NI ABUWE ENIKAN KII BA OMI SE OTA. OLORIN
AFRO OLOOGBE FELA ANIKULAPO, LO FI KORIN PE OMI KO LOTA,
BEENI KO SI EDA ENIYAN KAN TI YOO BA OMI SE OTA, BI O BA KO TI
ONI O KO WE, O GBODO MU OMI, OMI LAFI NSE OUNJE, OMI LA FI
NWE, OMI LA FI NFO ASO, OMI LA FI NFO MOTOR, OKADA TABI KEKE
WA TO BA DOTI. BI AISAN IBA SEJE, BI O BA KOLU ENIYAN, AWON
DOKITA YOO FA OMI SI IRU EDA BEE LARA KI O TO LE NI ALAAFIA
ASIRI LILO OMI
bi o ba ji ni kutukutu Owuro ki o to soro si eniyan,bu koopu omi kan(1CUP)gbe dani,da die sil ko duro le lori,maso bayi pe,Omi la bu mu,omi la buwe,enikan ki ba omi se ota,Okunrin lo baji to nmu omi,ko ma se binu simi,Obinrin lo ba ji to nmu omi,ko ma se binu simi,Omode lo ba ji to nmu omi,ko ma se binu simi,agba lo ba ji to nmu omi,ko ma se binu simi o. Emi L.OMO L.di ayanfe gbogbo aye loni yi,ema yonu simi bi e ti se nfe omi.
Leyin adura yi,e mu omi to wa ninu Cup,ema se be ni gbogbo owuro fun osu kan,e ma ri ayipada rere gbogbo ibi ti e ba de,ema ri oju rere awon eniyan
No comments:
Post a Comment