Saturday, September 30, 2023

ASIRI NLA FUN AWON TO FE DOLOMO LAYE 💯

ASIRI NLA FUN AWON TO FE DOLOMO LAYE 💯 


Eso Bara kan,Ewe Ejirin die,ao bo epo  eyin eso bara kuro,ao bu Omi Cup kan si,ao gbo papo dada tabi ki agun ninu Odo dada. Omi ti aba gbo jade ninu re,ao fi ase se,ao ro sinu igo tabi Plastic battle Rubber kan pelu Oyin original die.ao ma mu gasi kan ni Owuro ati Ale


IKILO PATAKI:
Odara fun Omokunrin ati Obirin ti won wa Omo tested and Comfirm Okay



FUN ENI TI OHUN WA OMO/PRAYER FOR FRUITS OF THE WOMB 💯

Battle water 1 kan,ao se ise yi ni Wednesday,Thursday,Friday pelu Awe Olojo 3 meta ati Adura ale gba awe di ago 12:00AM tabi 6:00PM bi agbara wa ba se gbe si,bibeli meji ni ao fi se ise yi,ao si bibeli kan si Psalm 127:1-3 ao gbe omi na le ao ni si Omo re o,ao ka Psalm 127:1-3 3x  Psalm 102:1-2 3x Deuteronomi 28:11 3x lati inu bibeli keji,ao ma pe Oruko mimo yi(BIRABA-ARABARIBI 21X)ni gbogbo akoko Adura wa 9:00,12:00,3:00,6:00 leyin Ojo keta,Obirin na yi o mu Omi yi

No comments:

Post a Comment

CONNECTION CLIENT SOAP GEE BOY 💯

 CONNECTION CLIENT SOAP GEE BOY 💯  Ewe Omisinmisin ti amo si eso oju Olohungbo Oojo tuntun die,ao fo Odidi eyin Ororo ibile ti o mo dada 1k...