AWON TO KO ILE AKOPATI (ABANDON HOUSE PROPERTY) 💯
OPOLOPO AWON ENIYAN LO KO ILE AKOPATI. ILE NI OMO ELOMIRAN
NKO LOWO, TI WON FI DA DURO LENU ISE. ILE NI OMO ELOMIRAN
NKO LOWO TI GBESE FI SE YO NIDI OKOWO RE. ILE LO GBABODE FUN
OMO ELOMIRAN, IWA IGBERAGA LO FA TI OMO ELOMIRAN, ABI KI LE
TI PE YOO RI, ENI TO FE SE IPILE ILE (HOUSE FOUNDATION) TO LO PE
OPOLOPO ENIYAN, ATI OTA ATI ORE, AWON TI INU WON KII DUN SI
OHUN RERE. GBOGBO WON LO MA NSE ADURA SUGBON ODIKEJI NI
ADURA WON. INU MI NI MO MO, EMI KO MO INU ENIKEJI MI. AWO
FELE BONU, KO JE KA RI INU ASEBI.
ONA ABAYO
E LO RA ODIDI AGBON NLA KAN (BIG COCONUT) E FO AGBON KAN
SINU IGO NLA FUNFUN KAN, EDA IYO ISEBE PUPO SI, EDA OYIN OGIDI
SIBI MEFA PELU RE, E LO RI MOLE, SI ORI ILE YIN. NI AGBARA
OLORUN ASIRI YIN YOO BO, E O RI OWO LATI PARI ILE YEN.
No comments:
Post a Comment