AWURE OJA TITA π―
AWURE SE PATAKI FUN OJA TITA BI BEEKO, ENIYAN YOO MA JE
GBESE LE GBESE NI.
BI OJA KO BA YA, ATI ERE ATI OJU OWO NI ONISOWO YOO MA NA.
ABALO ABABO, GBESE NLA LO MA DA SI ONISOWO LORUN. BI OJA BA
NYA, ERE NIKAN NI ONISOWO YOO MA NA, ASIRI RE YOO BO, LATI LO
RA OJA MIRAN SORI IGBA.
AWURE OJA TITA
Elo ja Ewe tomato tutu ti e ba fe ja e pe Oruko re ni ewe Onitikuti,e so pe Ewe Onitikuti 3x egbe Owo le lori ke pe Oruko re ni emeta,e so pe,mo fe be o ni ise kan,mo si fe ko bami je ise na. Ewe onitikuti ti awon eniyan Nla ti yio bami ra Oja wa loni yi,leyin na,Eja pupo Ewe tomato(Onitikuti)yen,e lo gun mo Ose dudu tabi Ose oyinbo. Ti e ba gun papo tan,e da sinu ike ff Olomolori kan. e da oyin ogidi sibi merin le lori,e ma fi we ni Owuro ki e to lo si ibi itaja yin
Adura. Onitikuti 3x lo ba mi ti awon onibara(Customers)ti yio gbe Owo Nla wa bami ra Oja ti mo Nta loni yi wa
IKILO PATAKI
ki efi Ewe Akoko Oojo tabi Ewe iyalode ff tabi pp ati otin ibile tabi Omi fo inu ati eyin ike ff na,lati le yo Owo Oja kuro lara re,
No comments:
Post a Comment