BI ASE NLO ATARE ATI OROGBO FUN AMARALE OKUNRIN ATI FUN AABO (PROTECTION) 💯
BI E BA JE ATARE ATI OROGBO PAPO, OKO OKUNRIN MAA DIDE,
OPOLOPO OKUNRIN NI KO LE SE DEEDEE LODO IYAWO WON.
WAHALA ATI IDAAMU LENU ISE LO SABA MA N FA EYI.
BI OKUNRIN BA GBIYANJU LATI MA A JE ATARE ATI OROGBO PAPO
NKAN OMOKUNRIN YO O MA SISE TOYE KO SE.
IKILO
BI ENIYAN BA NJE ATARE ATI OROGBO PAPO, MO FI OLORUN
ELEDUMARE BE YIN, E MA FI SE EPE FUN OMO NI KEJI YIN O. DIPO
BEE E MA FI GBADURA FUN IYAWO ATI OMO YIN.
FUN AABO
ESO EYO ATARE MESAN SINU PAPER KAN, E FI YI PO, KEE MA SO SINU
APO YIN. NI AGBARA OLORUN MOTOR YIN KONI DANU, ASITA IBON
KO NI SE KONGE YIN.
ISE YI TUN WULO FUN AABO NINU ILE, EFI OWU DUDU ATI OWU
FUNFUN WE ATAARE, ESO SINU APO YIN KEE MA MU KAAKIRI TABI KI E SO SI ENU ONA ABAWOLE YIN.
AABO OLORUN YOO DAJU LORI WA (AMIN).
No comments:
Post a Comment