Friday, September 29, 2023

BI ASE NLO EEPO OSAN MIMU FUN IBUKUN ATI IGBEGA LENU ISE 💯

 BI ASE NLO EEPO OSAN MIMU FUN IBUKUN ATI IGBEGA LENU ISE 💯 

BI A BA HO EPO OSAN MIMU TAN INU IGBO LA MA N DA EEPO RE SI, 

AIMOKAN LO SI N FA EYI. BI E BA GBO ASIRI BI ATI SE NLO EEPO 

OSAN MIMU, ODAJU PE E KO NI DA EEPO OSAN MIMU NU MO.

ASIRI NLA

ASIRI NLA KAN RE O, ADII TU NI ISE OLORUN OLODUMARE

AWON EROJA

EEPO OSAN MIMU, IYO ISEBE, IGO OYIN OGIDI KAN. E LO SA EEPO 

OSAN MIMU PUPO, E SA KO GBE DAADAA. TO BA GBE TAN, E LE LO 

LODO AWON ELERO OGI. TABI KI E GUN LOJU OLO, TI E BA GUN TAN 

TABI TI ELO TAN. E DA SINU IKE OLOMORI, E FI IYO ISEBE SIBI KAN SI, 

E DA ILAJI IGO OYIN OGIDI KAN SI. E MA LA NI OWURO.

ADURA RE

INU IGBO NI OSAN MA NWA OMO ARAYE LO MA NLA ONA LO SI IDI 

RE. GBOGBO OMO ARAYE, E MA FI OWO WA MI KAAKIRI LONI YI, E 

WA SEMI LOORE PATAKI, LEYIN ADURA YI, ETI IKA AARIN BO INU IKE 

OYIN YI, KEE TO LA NI EEMETA, KI E TO JADE NILE NI OWURO. E TUN 

LE LA NI ALE KI E TO SUN.

PELU ASE OLORUN OMO ARAYE YOO MA FI OORE NLA WA YIN KIRI NI

No comments:

Post a Comment

CONNECTION CLIENT SOAP GEE BOY 💯

 CONNECTION CLIENT SOAP GEE BOY 💯  Ewe Omisinmisin ti amo si eso oju Olohungbo Oojo tuntun die,ao fo Odidi eyin Ororo ibile ti o mo dada 1k...