BI ASE NLO EERU FUN ISEGUN OTA ATI WIWE EPE DANU 💯
YORUBA LO MA N SO PE, ENI TO DA EERU NI EERU MA NTO. BEENI,
ENI DA EERU NI EERU MA NTO. KOSI SUGBON TABI NIBE, ENIKENI TO
BA DA EERU SORI AKITAN EERU DIE YOO PADA SI ODO ENI TO DA
EERU NU.
LILO RE
E LO RA OSE DUDU, KEE PO PAPO MO EERU KEE MA FI WE NI
OWURO TABI NI ALE. TO BA JE OSE OYINBO LEFE LO, E LE FI OMI
GBIGBONA TABI OMI TUTU RE OSE OYINBO, TO BA RO TAN, EDA OMI
TO WA LORI RE NU. E PO EERU MO OSE YEN, E MA FI WE NI OWURO
TABI ALE
No comments:
Post a Comment