BI ASE NLO ERUPE OSAN ATI ORU FUN AABO 💯
ERUPE OSAN ATI ERUPE ORU NA WULO FUN AABO. BI E BA LO WA
ERUPE OSAN NI DEEDE AGOGO KAN OSAN 1:00PM, BI E BA TUN WA
ERUPE ORU NI DEEDE AGOGO KAN ORU 1:00AM, EDA MEJEEJI PAPO,
EDA SINU OWU OTUTU (COTTON WOOL) EDA EYO ATARE MESAN SI,
PELU ABERE OPORO (1 NEEDLE) E FI OWU DUDU ATI OWU FUNFUN
DI MORA WON E LE SO SI ENU SHOP, E LE SO SI ENU ONA ILE YIN
TABI KI E SO SI INU MOTOR YIN, E LE SO SI APO YIN, KI E MA FI SI ARA
KAAKIRI OSAN ATI ORU KII PADE ARA WON. PELU ASE OLORUN,
BURUKU KAN KO NI SELE SI YIN
No comments:
Post a Comment