BI ASE NSE ITOJU ESUKE (HICCOUGHS) 💯
ESUKE NI AISAN TO MA NFA OKAN SOKE, TO JE PE O NFA INIRA FUN
MIMI SOKE ATI MIMI SI ISALE. ESUKE MA NPA OMO ENIYAN, E JE KA
SO FUN ENI TI KO BA MO.
TI ESUKE BA PO LAPO JU, ORUN NI ALA FUN ALAISAN TI ESUKE BA
NDA LAAMU. ESUKE LE DAAMU OKUNRIN, OLE DAAMU OBIRIN, OLE
DAAMU OMODE ATI AGBA. BI AISAN YI SELE DAAMU OLOWO BEE LO
SELE DAAMU TALAKA TI KO ROWO YO LAWUJO.
ITOJU RE
E LO WA ELUBO PAKI FUNFUN (CASSAVA POWDER) E DA SINU OYIN,
EJE KI ENI TI AISAN YI NYO LENU, KO MA LA NI OWURO ATI ALE TO BA FE SUN
No comments:
Post a Comment