BI O BA NLA ALA BURUKU, TI O KO SI FE KO SE π―
BI O BA LA ALA BURUKU TI O SI FE KO WA SI IMUSE, O NI OHUN TI
AWON BABA NLA WA MA SE TI WON BA LA ALA BURUKU.
E MA SO PE ALA GOO, ALA KO GO RARA, ALA MA NSE OFOFO OHUN
TO FE SELE LOJO IWAJU NI.
BI O BA LA ALA BURUKU, AWON ALA TI KO DARA, AWON ALA PE O
JASI KONGA, O GOKE O JABO, ALA IJAMBA OKO ALA PE EJO BU
ENIYAN JE, ALA PE WON LU ENIYAN NI ALU DAKU.
ONA ABAYO
BI O BA LA ALA BURUKU, TO BA TI JI NI OWURO OJO KEJI, KI E TO
SORO SI ENIKENI, IGBE TI E KOKO YA E MA TU ITO SI LEMETA, E O SO
PE, TI ONI MI BA YA IMI, O MA N PATI NI, BI OMODE BA YA IGBE O
MA N PA TI NI, BI AGBA BA YAGBE, OMA NPA TI NI, ALA BURUKU TI
MO LA YI MO KOO SILE NI ORUKO OLORUN, KO GBODO SE MO MI LARA. LEYIN NAA AO RE DANU
No comments:
Post a Comment