BI O KO BA FE KI WON YE AGA MO O NI IDI 💯
BI OBA WA NI IPO NLA, TI O KO SI FE KI OTA YE AGA MO E NI IDI,
GBOGBO ENIYAN NI IPO OLA MA NWU, NITORI IDI EYI, GBOGBO ENI
TI O WA NI IPO NLA KOJOWO KO DI IPO NAA MU NITORI AWON
ENIYAN, WON LE PA IRO MO E, WON LE SE EKE, WON LE DI OTE ATI
RIKISI. GBOGBO E, GBOGBO E, LATI FI LE O KURO NI ORI AGA OLA NI.
ONA ABAYO
LO TOJU KOKORO OYIN PUPO DIE, AFARA OYIN DIE, TO IYO ISEBE
DIE, A O GUN GBOGBO RE PAPO, E DA SINU IKE OLOMORI, E DA OYIN
OGIDI LE LORI E MA LA NI OWURO KI E TO JEUN
No comments:
Post a Comment