BI OBA NFI OJU KO OWU ALANTAKUN 💯
BI ENIYAN BA NFI OJU KO OWU ALANTAKUN APERE BURUKU TI KO
DARA NI.
OHUN LO MA NFA AMUBO OKO, AMUBO AYA ATI AGBANA.
OWU ALANTAKUN WON KII FI DI IGI, OMO ENIYAN NI WON MA N FII
DI.
ASE IRI, ASEDANU, ASEE KOWO JO, LO MA NSELE SI GBOGBO ENI TO
BA NFI ORI KO OWU ALANTAKUN.
AARIN OJA, AARIN TITI NI OPOLOPO TI MA NFI ORI KO OWU
ALANTAKUN.
AWON AGBA (AWON AJE) LO MA NFA ISORO YI FUN OMO EDA
ENIYAN.
APERE PE WON NBA ENIYAN JA NI FIFI OJU KO OWU ALANTAKUN.
GBOGBO ENI TO BA TI NRI IRU APERE YI, KO JOWO TETE WA KUN
IRIN ESE RE NI O.
GBOGBO ISE LO MA DOJU RU, GBOGBO OJA LO MA BAJE MO IRU ENI
BEE LOWO, GBESE LO MA N DA SI ORUN ENI TO BA NI IRU ISORO
BAYI, ORE YOO MA SA FUN, AWON EBI YO O MA YERA FUN, JIJE MIMU YOO MA NIRA FUN.
ONA ABAYO
AYE KO NI GBONA TITI, KA GBA ONA ORUN.
AO JO MA GBE ILE AYE YI NI.
E LO RA EEPO OBO, ELO KO KUNNA DAADAA, EPO DIE MO OSE IWE
YIN, E LE PO MO OSE DUDU TABI OSE OYINBO, E MA FI WE NI
OWURO, TO BA WUN YIN, E TUN LE MA FI WE NI ALE KI E TO SUN.
E TUN LE DA SINU LOFINDA TO BA WUN YIN, KE E MA FI PA ARA NI
ALE KE E TO SUN. NI AGBARA OLORUN E KO NI FI OJU KO OWU ALANTAKUN KANKAN MO
No comments:
Post a Comment