BI A TI NLO OMI OJO FUN ASEYORI 💯
OPOLOPO NI KO MO PE OMI OJO WULO PUPO, YATO SI LILO LATI FO
ASO, TABI LATI WE. OMI OJO WULO FUN OMO EDA TO BA FE LU
ALUYO. OMI OJO TI MO NSO ORO RE YI, KO KI NSE OMI OJO LASAN,
OMI OJO TO BA KOKO RO NINU ODUN NI MO NSO. EGBE OMI OJO
AKOKO RO YI SINU IKE IWE YIN.
ASIRI REE
TI E BA FE FI OMI OJO YI WE, EDA IYO ISEBE DIE SI, KE MA SO PE, OJO
AKORO MA N GBON ERUKU OSI ATI ISE DANU LARA EWEKO IGBE NI.
OLORUN OLODUMARE JOWO WA GBON OSI ATI ISE DANU KURO
LARA MI. OGUN KOSIKOSI, BAMI WE DANU. LEYIN ADURA YI, ELO FI
OMI OJO NAA WE. PELU ASE OLORUN E O RI AYIPADA SI RERE
No comments:
Post a Comment