BI A TI SE LE DAABO BO DUKIA WA.(PROTECTION AGAINST BANDIT) π―
AWON BABA WA NI OGBON TI WON FI MA NDA ABO BO ERU ATI
DUKIA WON LAYE ATIJO. AWON KAN MA NSO IGBALE SI ENU ONA
ILE TABI SHOP WON. OLE TO BA WO ILE TABI SHOP BEE, YOO MA
GBA ILE TITI DI ALE NI.
ARA OGBON MIRAN TI AWON YORUBA TUN MA NLO NIYI. WON MA
N DA AGBADO SI INU IGO, WON MA N SO SI ENU ONA ILE TABI SHOP
WON. AWO MOJU NI ADIE MA NWO AGBADO INU IGO.
ASIRI RE REE
E DA AGBADO FUNFUN PUPO DIE SINU IGO FUNFUN, E DE PELU
OMORI, E LO SO SI AARIN AWON ADIE IBILE TO N JEUN LOWO. WON
MA POOYI IGO YEN LASAN NI, WON KO LE SE NKANKAN FUN
AGBADO ATI IGO. TO BA DI OJO IKEJI, ELO MU IGO YEN KURO,
NIWON IGBATI NKANKAN KO TI SE AGBADO INU RE. E LO SO IGO
AGBADO YEN SI ENU ONA SHOP TABI ILE YIN KODA E LO SO SI INU
MOTOR YIN. AWO MOJU NI A DIE MA NWO AGBADO INU IGO, PELU
ASE OLORUN, ABO TO DAJU YOO WA LORI DUKIA YIN.
No comments:
Post a Comment