BI WON BA DA OOGUN SILE LENU ONA ILE TABI SHOP RE π―
GBAJUMO OLORIN JUJU NI OLOYE EBENEZER OBEY LO KORIN, NINU
GBOGBO OHUN TI OLODUMARE DA SI AYE, AWA ENIYAN LA SORO. BI
ABA N BA ARA WA RIN, OHUNKOHUN LO LE SELE, NIGBAKUGBA TABI
LOJO IWAJU AWON ENIYAN LEDA OOGUN SIWAJU ILE RE TABI SHOP
RE.
IGBAMIRAN WON LE DA OOGUN SORI TABILI (TABLE) TO OTI NTA
OJA. AKO NI RI IJA AYE O.
AWON IKA, AWON ONILARA EDA, AFOJU FENI, MA FI OKAN FENI PO
TI AJO NGBE ILE AYE YI. A KO NI SALO FUNRA WA.
ONA ABAYO
BI O BA FURA PE AWON IKA ENIYAN TI DA OOGUN SILE LENU ONA
ILE RE TABI SHOP RE. LOO RA IYO PUPO, DA SINU OMI, DA OYIN
OGIDI SIBI MEFA PELU RE. FIFO ENU ONA ILE RE, FIFO ORI TABILI
(TABLE) TO O TI NTA OJA. LEYIN NAA FON IYO SI GBOGBO ENU ONA
ILE RE.
IKILO
OGBON LO GBA O, IYO LO MA FON SI ENU ONA SHOP RE O, MA JEKI
AWO OTA MO PE, ASIRI WON TI TU SI O LOWO PELU ASE OLORUN,
IWO YOO BORI WON.
AWON TO FURA PE OJA AWON KO TA BO SE NTA TELE MO, LE SE ISE
YI, NITORI KOSI OHUN TI AWON OTA KO LE SE. AWON
No comments:
Post a Comment