ERO MAJELE 💯
OLORIN EMI KAN LO KORIN PE, OHUN TO N WUNMI, KO MAPAMI
LARA, OHUN TI YOO PAMI KO MASE WUN MI O. ATENUJE KONI
PAWA O, NINU GBOGBO OOGUN TI AWON OMO ARAYE MA N SA SI
ENIYAN. WON LE DA OOGUN SILE FUN ENIYAN, WON LE BU ESE
ENIYAN, WON LE FI OOGUN SI ORI IJOKO FUN ENIYAN, WON LE FI
ORUKA BURUKU, ORUKA ERE BO ENIYAN LOWO, WON LE PE ENIYAN
NI APEPA LATI OJU OORUN. GBOGBO RE, OLORUN LE KO EDA YO.
EYI TO BURU JU NI KI WON FI MAJELE SINU OTI TABI OUNJE FUN
ENIYAN. OWO ORUKA NI AWON KAN FI MA NGBE OUNJE TABI OTI
FUN EDA ENIYAN. OLORUN KO SO WA LODO AWON TO N SO NI, TI
AWA KOSO. IGBA MIRAN MAJELE OUNJE LEWA LATI OWO AWON TI
O N TA OUNJE TUTU BI EWA, ISU, IRESI, AGBADO ATI BEEBE LO, TI
WON BA FI KEMIKA APA KOKORO SINU AWON OUNJE TUTU TI WON
NTA KI KOKORO MA BAA JE GBOGBO RE TAN.
EYI YOWU TO BA J,E BI O BA SE AKIYESI PE INU RIRUN N DA O LAAMU
LEYIN TI O JE OUNJE TABI MU OTI TAN. AKIYESI NI ORO RE GBA, TO
BA JE OMO RE LO TI ILE IWE DE, TO NLO INU MOLE, PE INU NRUN
OUN, E TETE LO OOGUN SI KOTO PEJU
ASIRI TI MO FE KOYIN YI MO TI KO YIN RI LORI YOUTUBE. OPOLOPO
AWON ENIYAN LO PEMI, TI WON KI MI KU ISE OPOLO.
ERO MAJELE
EPO PUPA SIBI MEJI, OYIN OGIDI SIBI MEJI, EDA PAPO KI ENI TI INU
NRUN TO FURA PE OUN JE MAJELE KO GBE MU. NI AGBARA OLORUN
ENI NAA YO LO SI ILE IYAGBE, YOO YA GBOGBO RE DANU TABI KO BI DANU (VOMIT IT).
No comments:
Post a Comment