ERO OFA TABI ATA TI WON SO ENIYAN 💯
OLORUN MA JEKI A RI IJA OMO ARAYE O. OLORIN AWUREBE ALHAJI
DAUDA EPO AKARA KI OLORUN TE SI AFEFE RE, O KORIN KAN PE
OLORUN MAJE NSE WON O, OLORUN MAJE NSE WON O, ENI TI A O
SE, TI KO NI GBO EBE O.
OLORUN MA JEKI NSE WON O, AWON IKA PO LAYE YI, AFOJU FENI
MA FOKAN FENI, AMONI SENI, A FAI MONI SENI, ASENI BA NI DARO.
GBOGBO WON NAA LAJO NGBE ILE AYE YI.
ILE AYE YI KO SI NI GBONA TITI, KA GBA ONA ORUN LO, AAJO GBE IBE
NI. ARA ONA TI OMO ARAYE FI MA N BA WON JA. TABI DA SERIA FUN
ARA WONN NI KI WON TA OMO ENIYAN NI OFA TABI KI WON SO NI
ATA.
ATA NI WON SO ELOMIRAN ESE RE JERA TO FI KU NI, ATA NI WON SO
OMO ELOMIRAN OYAN RE JERA MO LAYA NI, KI WON TOO GBE SIN
SINU KOTO.
OMO ARAYE LE, E BERU ENIYAN EDA OMO ADAMO WON LE BINU RE
NITORI OWO. WON LE BINU RE NITORI MOTOR, WON LE BINU RE
NITORI IPO GIGA TI OBA GBE O SI
ONA ABAYO
BI WON BA TA O NI OFA TABI WON SO E NI ATA MA BERU OLORUN
NBE PELU RE.
E LO WA EWA FUNFUN AGOLO KAN, AGBADO FUNFUN AGOLO KAN.
GUN MEEEJI PAPO, KO O KUNNA DAADA, E LE FI AJO JOO. TI E BA FEE
LO, E MA DA SIBI IMUKO OOGUN TI E SE YI SINU OTI SCHNAPP TABI
CHELSEA TABI OGOGORO. EDA SIBI IMUKO OYIN OGIDI MEJI SI. E MA
MU NI OWURO, PELU ASE OLORUN, ORO OFA TABI ATA TI WON SO
YIN YOO MA BA ITO ATI IGBE JADE NI
No comments:
Post a Comment