EYONU/ IFERAN 💯
EYONU NI AWON ENIYAN NPE NI OBA OOGUN. ENI TO BA TI NI
EYONU LARA, GBOGBO AYE NI YOO MA FERAN RE TI WON YOO SI
MAA YONU SI.
ENI TI AYE BA YONU SI, BO BA GBE OJA SILE, YOO MA TA
WARAWARA NI.
ENI TI AYE BA YONU SI GBOGBO OHUN TO BA TI DAWOLE YOO MA
YORI SI RERE NI.
BI E BA LO OOGUN IFERAN NAA YOO MA SISE BI EYONU NI
ASIRI
EWE EWURO TUTU TABI GBIGBE E GUN PAPO MO OSE OYINBO TABI
OSE DUDU, EFO EYIN ADIE IBILE KAN SI, E DA OYIN OGIDI SIBI META
PAPO MO, E RO GBOGBO RE PAPO MORA WON.
E DA OMI AGBON KAN SI, LEYIN TI E BA TI RO PAPO TAN. E GBE SINU
IKE OLOMORI FUNFUN KAN, E MA FI WE NI OWURO KEE TO JADE
NILE.
ASIRI YIN YOO MAA BO, E KO NI NA OWO KAN TAN KI E TO RI OMIRAN
No comments:
Post a Comment