IROYIN AYO FUN GBOGBO ALABOYUN 💯
GBOGBO EYIN ALABOYUN TO DIWO DISE SINU. OLORUN YOO SAANU
YIN, E SOKALE LAYO, ASOKALE ANFAANI FUN GBOGBO ALABOYUN.
EMA SO PE AYE DI AYE OYINBO, KEE MA FOJU EGBO DE ILE KIRI,
AWON BABA WA MA NSE ASEJE ABIWERE ORISIRISI FUN AWON
ALABOYUN, WON MA NSE OSE TUDE FUN WON NITORI AWON IKA
ENIYAN TO MA NDURO DE ALABOYUN NI OJO IKUNLE. TI OMO BA
DUBULE, TO BA FE MU ESE JADE AWON BABA WA MA NDA OGBON
SI, OLURUN SI MA NGBA FUN WON. NI OJO KAN, EWURE KAN FE BI
OMO, OGBIN TITI, OMO KO JADE, EWURE YI BERE SI KE, O N
SUNKUN, O NLA OOGUN, EWURE YI OWO TITI, O KANU RE, BI
EWURE YI SE YIPADA, O SARE LO JA EWE EWURO WA FUN OMO RE
TO N ROBI LOWO, ASIRI KAN RE O. FUN GBOGBO ONI LAAKAYE
ENIYAN. MO FI ASIKO YI RO GBOGBO AWON ALABOYUN LATI MAA FI
EWE EWURO SINU EFO TIWON NSE NI OBE.
BI ALABOYUN BA SI JE EWURO TUTU NI OJO IKUNLE, PELU ASE
OLORUN, IRORUN NI OJO IKUNLE YOO JE.
ASIRI YI WA FUN AWON OLOGBON ATI ONI LAAKAYE EDA. AWON TI
ESIN OYINBO KO TI PA OGBON IMO, OYE ATI LAAKAYE WON. OGBON
NBE, ENIYAN WA.
OLORUN NI BABA GBOGBO WA
No comments:
Post a Comment