ITO SUGAR TABI ATOGBE 💯
ITO SUGAR ATI ATOGBE ORUKO WON YATO SI ARA WON, SUGBON
IWA WON JORA WON. ENI TO BA NI AISAN ITO SUGAR YOO MA TO
LERALERA NI, ALAISAN ITO SUGAR LE TO ITO KUN IKE ODA KAN NI
ALE KILE O TO MO NI OJO KEJI (4 LITRES KEG). ITO ALAISAN ITO
SUGAR MA N DUN NITORI RE NI ESINSIN SE MA N PE BO ITO WON.
SUGBON ITO AWON ALAISAN ATOGBE KO KI N DUN, EERA KII PE BO
ITO TIWON, BEE NI ESINSIN KII PE BO ITO WON IDI RE NI YEN TI
AWON ALAISAN ATOGBE KII FI TETE FURA WIPE AISAN ATOGBE IKEJI
ITO SUGAR TI N DAAMU AWON.
ENI TO BA NI AISAN ITO SUGAR TABI ATOGBE YOO MA RU, YOO MA
GBE NI, NNKAN OMO KURIN WON KO NI SISE DEEDEE MO, NITORIPE
GBOGBO FITAMIN (VITAMINS) ARA WON NI WON MA NTO DANU.
AISAN ITO SUGAR NSE IKU PA OMO ENIYAN, BEENI AISAN ATOGBE N
RAN OPOLOPO ENIAN LO SORUN APAPA NDODO. BI AISAN ITO
SUGAR BA POJU, O LE SE ATONA FUN AISAN ROPAROSE.
A KONI FI OJO LOJO LO O, ENI TI AISAN BA NSE, KO TETE SE ITOJU TIRE
ITOJU AISAN ITO SUGAR
BI AISAN ITO SUGAR BA N YO E LENU, BO BA SI JE ATOGBE NI AISAN
TIRE. WA A GBO ASIRI RE:
E LO WA EGBO MADUNMARO PUPO, E GE WEWE SI KEEGI (5 LITRES)
E DA OMI LE LORI FUN OJO META LEYIN OJO KETA, E BERE SI MAA
MU OMI INU RE. NI AGBARA OLORUN, LEYIN OJO META, E LO SE
AYEWO ARA YIN. WON YOO SO FUN YIN PE KEE MA DUPE. ADURA
YIN TI GBA.
ONA KEJI
E TUN LE DA EGBO MADUNMARO YI SINU OTI OYINBO KEE MA MU
GAASI KAN NI OWURO, GASSI KAN NI OSAN ATI GAASI KAN NI ALE.
PELU ASE OLORUN, E O DUPE LOWO OLORUN.
IKILO PATAKI
BI E BA TI RI AYIPADA RERE, E DAWO MIMU RE DURO NITORI KO YE KI SUGAR ARA TUN LO SI ILE JU
This comment has been removed by the author.
ReplyDelete