ITOJU AISAN WARAPA π―
AISAN ADOJU TINI NI AISAN WARAPA.
AISAN YI KO MO ASIKO OJO YATO SI ASIKO EERUN, IGBAKUGBA LO LE
KI ENIYAN TO BA NSE MOLE. TI IRU ENI BEE YOO SI MAA PO ITO
LENU.
AISAN YI A MA SE OKUNRIN BEENI O MA NSE OBINRIN PELU.
OMODE LE NI AISAN WARAPA, BEENI AGBALAGBA LE NI AISAN
WARAPA.
OMO ARAYE LE FI AISAN YI SE ENIYAN. BI WON BA DA OOGUN SI ARA
ASO TI ENIYAN SA SITA.
AJOGUNBA NI AISAN YI JE FUN ELOMIRAN NITORIPE TI BABA TABI
IYA BA NI AISAN WARAPA, OMO TI WON BA BI NAA YOO NI AISAN
WARAPA.
ITOJU RE
BI E BA FE SE ITOJU AISAN WARAPA. E LO RA KIRETI EYIN APARO KAN
(1 CRATE OF QUAIL EGGS) EFO EYIN YEN SINU IKE TO BA FE NLA KAN,
EDA IGO OYIN OGIDI KAN SI, E RO PAPO MO ARAWON.
LILO RE
KI ENI TO NI AISAN WARAPA MAA MU, SIBI OOGUN YI META NI
OWURO, SIBI META NI OSAN ATI SIBI META NI ALE PELU ASE
OLORUN, AISAN NAA YOO LO
No comments:
Post a Comment