TI O BA FE KI OYAN RE TOBI π―
AWON OKUNRIN FERAN KI OYAN OBINRIN TOBI DAADA NITORI BI
WON BA WA LOKE ARAFA (LOKE OBINRIN) WON FE KI AWON TUN
MA MU OYAN PELU RE.
OYAN TO KERE, O MA NFI IYA JE OLOYAN NI, ASO KII DURO DAADA
LORUN OBINRIN TI KO BA NI OYAN TO TOBI.
MO TI GBO TI OKUNRIN KO IYAWO RE SILE NITORI OYAN IYAWO RE
KERE. NIGBA TAA WA NI KEKERE, AUNTI WA KAN LO SI ILE OKO LAI JE
PE OYAN RE TI YO SI ITA. KO SA DEEDE LO O, OKO AFESONA RE, LO JI
GBE LASIKO TI AUNTI FOLAKE KIRI EKO LO SI ABULE KEJI.
IFE TO WA LAARIN AWON ARA ABULE WA ATI AWON ARA ABULE
KEJI KO JEKI WON SO ORO NAA DI IJA REPETE. KI N MA FA ORO GUN,
EKUN NI MAMA AUNTI WA NSUN PE OMO TI OYAN RE SI KERE, BOBA
FI LO NI OYUN, KI NI OMO RE FE MAA JE. OUNJE OMO (BABY FOOD)
KO TI WOPO LASIKO TI MO NSO YI,
BAYI NI BAALE ABULE WA SE PE MAMA AUNTI FOLAKE PE KO LO JA
PANDORO WA LATI OKO KI AWON FI SE ISE OYAN FUN UN. EMI NI
TIYIN NI TOOTO, WON SE ISE OYAN FUN AUNTI LEYIN OSU META
AUNTI WA DI ENI TO NI OYAN TO TOBI NI AYA
OGBON NBE, ENIYAN WA. AWON BABA WA NI OGBON ATINUDA
LOWO
ASIRI RE
BI O BA NI OYAN TO KERE JU OJO ORI RE LO, TO NDOJU TI O LAARIN
ORE TABI NI ODO OLOLUFE RE. LO RA ESO PANDORO TUTU TI
GBOGBO ARARA RE PE, TI KO TII RA, TI KO TII BA JE.
FI ADA GE SI WEWE, KO O SA SINU OORUN, KO FI GBE DAADA. TO BA
TI GBE TAN, E LO DA SINU ODO KEE GUN KO KUNNA DAADA. TO BA
WU YIN, E LE GBE LO SI ODO AWON ELERO TO MA NLO ELUBO KO BA
YIN LO KO KUNNA, TO BA KUNNA DAADA, E O MA BU DIE SINU OORI,
E O MA FI PA ORI OYAN YIN NI OWURO ATI NI ALE TI E BA FE SUN.
PELU ASE OLORUN, OYAN YIN YOO MA TOBI SII.
TI E BA TI SAKIYESI PE OYAN YIN TI TOBI TO BI E TI NFE, E NI LATI
DAWO DURO LORI LILO OOGUN YI, KO MA DIIPE OYAN YIN YOO TOBI
JU BO TI YE LO.
PANDORO
ENGLISH NAME: AFRICAN SAUSAGE FRUIT
YORUBA NAME: PANDORO
BOTANICAL NAME: KIGELIA AFRICANA
HAUSA NAME: HANT SAR GIIWAA
IGBO NAME: ALA NWANYI NGBOLOGODO ALA
No comments:
Post a Comment