Friday, September 29, 2023

OBA EYONU (GENERAL LOVE) 💯

 OBA EYONU (GENERAL LOVE) 💯 

Asiri Na Re. E lo wa Korofo eyin ti adie ti pa omo inu re kuro,Ewe Ola gbigbe die,e lo  kuna dada,e da die sinu ipara yin(BODY CREAM)e da die sinu oyin  ogidi,ojulowo oyin ti ko labula,e ma la owuro,to ba wu yin e da die sinu atike (FACE POWDER)pelu ase Olorun,eni to ba lo ise yi,yo ma ba oju rere Olorun ati eniyan pade nibikibi to ba de
Adura Re. Enu ni abere fi ma ntun aso se,enu ni ade fi ma n tun eyin re se,ona ki,ki adie ma ri aaye de idi eyin to n se aba le lori

No comments:

Post a Comment

CONNECTION CLIENT SOAP GEE BOY 💯

 CONNECTION CLIENT SOAP GEE BOY 💯  Ewe Omisinmisin ti amo si eso oju Olohungbo Oojo tuntun die,ao fo Odidi eyin Ororo ibile ti o mo dada 1k...