ORO NIPA IRAWO ATI OHUN TIOBAA IRAWO OLUKALUKUMUN LAYE ๐ฏ
Opo Obi loti da igbese aiye omo re ru nipa pe dandan ise bayi bayi ni o gbodo ko,Olukuluku eda ni Olohun ti fun ni ise ti yio maa se laye, sugbon latari agidi ti awa omo Eda Adamo ni koje ki a ni ifura. Oro Olohun ko le ye omungo Eda sugbon Ologbon eni ni nye,Opo ti o yeki o lo se ise Briclayer sugbon alakiyesi ko je ki o tete yan ise ori re layo,Eda ti o baa je omi laye ti o baa nse ise ina kole ni aluyo laye,eda to si je ina ti o nlo nse ise omi kole ni ilosiwaju laye. Imo nipa Irawo se koko laye awa omo eda,eleyi a jeki eda mo iru igbese aiye ti o le gbe,ohun ti oye ki a maa se ati ohun ti koye ki ase. Eda ti OIohun da lati ara omi ti o waa nlo se ise ni ile ise Bread,ki se epe raara kole ni aluyo laye. Ti abati bi omoEjeki a gbiyanju ki a to awon to ni imo nipa Isab wiwo ki won se alaye lori Iru irawo ti omona agbe waasi aiye,iru ise ti ole se.
*๐๐พ1. IRAWO ATEGUN*
Irawo Ategun je irawo to ni agbara pupo,bi walah batile po ju fun awon iru irawo yii igbeyin won maa nda pupo, won nma se orire lehin opolopo walahi,oju awon iru eda bayii maa ni opolopo wahala ni aiye won,oju won ki gbe ibikan raaraa,ti won baa nse ise kan won atun pa ise naa ti won a tun gba ibi ise miran lo.
*๐๐พIKILO FUN IRAWO AFEFE*
Oro awon eda bayi da gegebi eniti o ngbe kanga ti o waa de aye kan ti kanga yii ko waa kan omi,okuro ninu kanga naa,otun bosi ibo miran lati gbe kanga miran, be gege ni yio se maa gbe kanga yen lo titi ohun gbogbo ire yio fi tan mo lowo. Itumo oro yii ni wipe,Gbogbo igbati o baa ti gba ise kan mun mase maa kuro ni ibe ayafi fun idi kan
*๐๐พISE TO DARA FUN IRAWO ATEGUN*
Irawo Ategun gbodo je irawo to lo si school to keko gba oye (Graduate) idi ni wipe Irawo yii ohun ti won le fi jeun laye won ni Ise Akowe, iru won ni won maa ndi President, Governor ati bebelo. Awon die ninu ohun ti omo irawo Ategun le se ni awon wonyi
*๐๐พ1. 2. 3. 4. 5. 6. 7.*
Mass Communication Publisher Alfa Pastor Advitisment Pilot Transportation Gbogbo ohun ti o baa ti baa ategun mu laye
*๐๐พIKILO PATAKI FUN IRAWO ATEGUN*
Irawo Ategun gbodo so ara gidigidi, Irawo Ategun gbodo je eniti o ntera mo Adura ni gbogbo igba, Ewe ati Egbo maa ntete je fun irawo Ategun ni idiwon ti won baa tin se adura daadaa, Irawo ategun gbodo munra si sise Ogun Isori daadaa, toripe won ki je ki won de ibi giga ti won nlo laye, Irawo ategun gbodo maa sora ni aye kaye ti won baa tin se epe pupo toripe Ada awon eda yii lati ara ategun, asasi ntete maa ja lara opo ninu awon omo ategun pupo, Egun idile baba nsaba maa nja iran omo ategun pupo ti ki jeki won tete de ibi giga ti won nlo laye. Kiyesi,Alakala bi ki won maa je ounje oju oru,tabi ki wonmaaniajo sepo ni oju oru.
*๐๐พ2."IRAWO OMI"*
Irawo omi lagbara pupo, Asasi ki saba jaa won, sugbon egun idile baba nsaba maa nba won jaa pupo, Ewe ati Egbo ki sise lara won rara, Irawo omi ni obinrin iru won ni won ki gbe ile oko,won ki gbe ile oko toripe okunrin maa ngbe won ju sile ni,won a maa ni ewa pupo sugbon ogun promise and fail maa npo fun won pupo,Okunrin won maa nife si ki won maa yan ale pupo.
*๐๐พIKILO FUN IRAWO OMI*
Irawo Omi gbodo teramo Awon unkan isori pupo lati ibere pepe aiye won, Okunrin won gbodo sora fun isekuse toripe obinrin maa nda irin ajo won ru pupo toripe won nma nife si ale yiyan
*๐๐พISE IRAWO OMI*
Die ninu ohun ti Irawo omi le maa se
*๐๐พ1. 2. 3. 4. 5.*
Navey Seaman Doctor or Nurse Tita Eja tutu Pure water Gbogbo ohun ti o baa jomo ise omi
*๐๐พ3 IRAWO INA*
Irawo ina je irawo to ni agbara ju gbogbo irawo lo laye,Sugbon bi won se buru to Omi ni nmanfa akoba fun opolopo won. Enia giga ni won pelu laye, Opo ninu won maa nje alawo pupa, Ewe ati Egbo ntete maa je lara won bi unkan ti won baa jo lori ina
*๐๐พIKILO FUN IRAWO INA*
Irawo naa gbodo sora fun obinrin pupo, bi irawo ina baa se tan lati fe iyawosile o gbodo se iwadi daadaa toripe bi okunrin baa je irawo ina ti o baa le baa obinrin ti o je irawo omi pade, iru won ki gbadun ara won ninu ile, Omi yii sini yio maa paa ogo ina. Bi won baa ti njo ni ajosepo, beni omi yio se maa pa ogo ina re.
*๐๐พISE IRAWO INA*
Awon die ninu ise irawo ina
*๐๐พ1. 2. 3. 4. 5. Etc*
Solider Airforce Tailor Hotel Caterer
*๐๐พ4. IRAWO IYEPE*
Irawoiyepe je irawo ti won nsaba maa ni oju anu pupo, won je eniti o le soro dada, won ni ogbon pupo, sugbon iwa igberaga nma nba ise opo won je, won feran iwa imo toto. Inakuna sin ma nda won lamun pupo
*๐๐พ IKILO FUN IRAWO IYEPE*
Irawo iyepe gbodo so ara won gidi gidi nipa ina kuna, Bi suru awon irawo yii se po to be na ni ori kunkun won se po to nigbati o baa nbinu, sora fun inu fufu, sora fun iwa tara eni nikan.
แปlแปrun koni jeki afi แปwแป ara wa se ara wa
Ki Olorun siju anu wo gbogbo wa
GBIYANJU KO NI IWE
ASIRI IRAWO EDA LOWO
GBรYรNJร LATI SE รWรRร ARA-RE KII OMABA WรYร ASรN
No comments:
Post a Comment