SARA SISE FUN GBOGBO IRAWO TOWA LODE AIYE PATA-PATA ๐ฏ
ORO SOKI LORI RE.
Mofe kamo pe gbogbo igba koni ogun sise tabi eto adura sise, papa julo,taba ni kawo esin towa ni nigeria wayi loni tabi loke okun ( abroad) lofi owo si sara sise,koda ninu imo ijinle saara sise yara tunisile lowo ogun aiye ju wiwe ose tabi lo ogun kookan lo, odara kia mase sara fun irawo wa, ki ona lema la funwa,opolopo eda ni komope ohun ni irawo kookan, tabi mo nipa irawo kookan, opolopo awon elomi lodemo nipa irawo,sugbon tiwon komo nipa saara to romo irawo won.
Ki olorun maje ki awaye asan ni
Kosi ojo ti akolese saara fun irawo wa,bee sini kosi igba tabi akoko ti akolese saara na pelu.
Ema bami kalo nitori enibalo lobaku,
๐๐๐๐๐๐
(1) IRAWO INA
bio base akiyesi pe,nkan kolo dede gbiyanju kio fi awon nkan wonyi se saara,oka baba funfun,agbado pupa,aadun,gbiyanju kio mase saara yi pelu adura ni emeji losu,bukata re yio ma biya,pelu ogo lodo oluwa olorun awon omo ogun
(2) IRAWO AFEFE
oba irawo ni irawo yi,kosi gbogbo ibiti aaye koti gba irufe irawo bayi nitori pe oba irawo ni,bi irawo yi bawa ninu idanwo kan,tabi isoro kan,tabi owa ninu ogun iponju-airije-airimu,kio fi awon nkan wonyi se saara,omi, ohunje,owo(money)iyeti agbara re bagbe niooo,aso( cloth)aso eleyi ti oba nife ju ninu awon aso re nioo,eyiti otumo sipe aso re eyiti obati nwo tele nioo,kio fun awon arugbo ati afoju obirin,ni awon nkan saara yen,pelu ogo lodo olorun oba iseda aiye ati orun,bukata re yio biya pelu ogo oni majemu ayo
(3) IRAWO OMI
irawo omi je irawo alagbara, tosi kun fun opolopo omo elegbe ninu,gegebi apere,emere omi,iranse aje,iranse omi,omi anu, omi aje,emere iyepe, emere okuta, ati bebelo,bi iru irawo yi bawa ninu isoro kan tabi ikeji gbiyanju kio fi awon nkan wonyi se saara fun eniyan tabi kio da sinu odo tonsan,ekuru,sweet,biscuit,osan,ireke,sugar,bukata re tabi isoro re yio si biya pelu ogo lodo olorun oba gbogbo aye ati orun
(4) IRAWO ERUPE
edakeda toba nlo iru irawo yi,tio bani isoro tabi wahala lonakona tabi omiran,kio gbiyanju lati mafi awon nkan wonyi se saara ki ona re laa fun botife ati boseye,oyin,epo pupa,isu,agbon,
Pelu agbara toni majemu aiye irawo eni kookan wa lodo oluwa koni jeki awaye asan loruko Jesu Amen
แปlแปrun koni jeki afi แปwแป ara wa se ara wa
Ki Olorun siju anu wo gbogbo wa
GBIYANJU KO NI IWE
ASIRI IRAWO EDA LOWO
GBรYรNJร LATI SE รWรRร ARA-RE KII OMABA WรYร ASรN
No comments:
Post a Comment