GBOGBO OUN TINBA SELE SI ENIYAN KO NI OGUN AYE OOO 💯
AFOWOFA LOPO JU
DIE NINU OGUN TOHUN JA EDA LAMU NINU AIYE , READ IT WELL
[1) Bi obinrin base nkan osu re bi oba sesi so nkan osu re sibiti ekute ile ti legbe ti ekute ile bagbe bi o ba loyun ni ipari re omo naa yoo jale ni igbesi aye re (jaguda.olosa)
( 2) Bi obinrin bawa ninu oyun ti osi je asa re lati maa towo bo apo oko re ki o maa mun nkan nibe omo ti oba fi oyun nan bi yoo je odaju omo yio si maa jale pick pocket.
[3) Bi o ba je pe pelu agidi tabi agbara ni okunrin nlo lati ba iyawo re lajosepo lehin ipari nkan osu re bi obinrin naa ba loyun iru omo be yio je ipata omo ti yio malu awon obi re koni bowo fun enikan
[ 4) Bi okunrin ba da aso iyawo re bora sun ko dara rara osi ati ifaseyin ni maa fa fun okunrin.
[5)Bi iyawo wa ba gba Ile inu ile tan bi o ba gbe fun omo re okunrin kekere kolo danu si ibi ti won dale si osi lo manfa fun omo naa lojo iwaju ti omo naa ba dagba ooo
[6)Bi obinrin ba mon binu LASIKO iba lopo osi lomanfa fun oko
[ 7) Bi obinrin koba fi inu didun ni asepo pelu oko re bi ibalopo yi badi oyun omo naa koni laanu loju koda koni ni idarijin rara alaigboran omo ni yio ya boba dagba
[8) Obinrin tabi okunrin ko gbodo tuto tabi ko woto danu nigbati oba dide lori obinrin tabi lori okunrin bi ibalopo naa badi oyun omo yi ti won yio bi osese ki omo naa ni arun warapa tabi ogun oruu
[9)Bi obinrin ba loyun ko gbodo ma joko senu onaa yoju sode lenu onaa nitori ojo ikunle re obinrin naa koni tete wale ati wipe bomo naa ba dagba yoo feran eke sofo ati ejo elejo ni riro oju mi tole oju mi to oko ni yio mase kakiri sa.
No comments:
Post a Comment