Thursday, June 3, 2021

ORUKO AWON MALAIKA KOOKAN TIA LEFI BEE OLORUN ISEDA WA NI OJO KOOKAN 💯

ORUKO AWON MALAIKA KOOKAN TIA LEFI BEE OLORUN ISEDA WA NI OJO KOOKAN 💯 

Odara lati mafi bee Olorun oba wa lojo kookan,osi ma njeki adura tete gba lati fibe olorun mose lojo lookan, osi tun ma njeki adura tetegba nigbati abatimo oruko malaika tosilkun ojo kookan, tia simo bi asele figba adura ki adura na tete wole ase


(1) MONDAY,( holy gabriel   (2) TUESDAY, ( Holy Raphael,  (3) WEDNESDAY,( Holy uriel

(4) THURSDAY,( Selaphiel

(5) FRIDAY, ( Holy raguel or jegudiel  (6) SATURDAY, ( holy barachiel. (7) SUNDAY, ( Holy micheal  


Ipinre ni iseda re, loruko jesu iwo yio sise aseyori ohun rere

EJEKA TUN MENUBA AWON ORUKO OLORUN TIA LEFI GBADURA ATI ITUMORE APAKEJI


NAME. (1) ELOHIM -- STRENGTH----(OKUN)


(2) YAWEH. gen3:13-14-----I AM ( EMI NI)     (3) ABRA ------ FATHER ( BABA)


(4) EL ELYON ----- GOD MOST HIGH ----- OLORUN TIO GA JULO


(5) EL ROI gen16:13----- GOD SEE ALL ( OLORUN TIO RI OHUN GBOGBO


(6) EL SHADAI grn 17:1-3---- GOD ALL MIGHT( OLORUN ALAGBARA  


(7) YAWEH,,gen22:11-13---THE LORD WILL PROVIDE( OLUWA YIO PESE


(8) YAHWEH-NISI------ THE LORD IS MY BANNER----OLORUN NI OJIJI MI


(9) JEHOVAH RAPEAL exo15:26-----HEALLER( OLUWO SAN)


(10) YAHWEH-SHALOM----- THE LORD IS PEACE( OLORUN ALAFIA


BIA BAMO LILO AWON ORUKO OLORUN YI, TIA SI NLO NINU ADURA WA LESEKESE NI ADURA WA YIO GBA, EJE KAMOPE ORUKO OLORUN JEJU OGUN LO

No comments:

Post a Comment

CONNECTION CLIENT SOAP GEE BOY 💯

 CONNECTION CLIENT SOAP GEE BOY 💯  Ewe Omisinmisin ti amo si eso oju Olohungbo Oojo tuntun die,ao fo Odidi eyin Ororo ibile ti o mo dada 1k...