ÀMÌ BURÚKÚ NINU EBI 💯
Kii ọlọhun siju anu wo awa eda eniyan nitoripe ọpọlọpọ bẹni nii wàhálà ati idamu ùn dojú kọ ṣugbọn olohùn nikan ni ole b'awọn tán ìṣòro wọn pẹlu Àmì buruku yii wa ninu ọpọlọpọ ebi bẹ sini latara Àlá lila Ami buruku yii ma ùn wọ inú Aye ẹdá
Paapa julo ejeki aso nipa Ami buruku yii tii owa ninu ebi gẹgẹ àpẹẹrẹ
*Nje iwọ Mope awọn iran kan wà toje pe won kii ùn nii owó lọwọ Ami yii kii unse ikan tii oba ojumu.
*Nje iwọ Mope ọpọlọpọ obìnrin nii ọjọ oriwon ti lo ṣugbọn wo kori okunrin ko enu ife siwọn bíi Ami buruku yii bawa lara obinrin kosi bíi osele rẹwa to koni lọkọ
*Nje iwọ mọ pé awọn iran kan wà toje pe Ami Àìrí ile ọkọ gbe nii Ami buruku arawọn besini awọn òbí wọn kii nfẹ kii won nii ọkọ besini obi ẹlòmíràn nii Ami buruku tii ayé fi sí lára
*Nje iwọ pé àwon ìdílé kan wà ti ojepe wọn kii ùn lo ju 40 years lo nile ayé eyiti obalo koja 40 years ajepe omura síi ọrọ aiye ee ṣugbọn kii unsaba wọ pọ ninu ebi wọn
*Nje iwọ Mope awọn idile kan wà tii wọn kii ùn lu Aluyo oun réré ni igbesi Ayé wọn òsì ati idamu nii ounjẹ wọn ipọnju ati wàhálà nii ayanmọ tiwọn
*Nje iwọ mọ pé àwọn idile kan wà tii ojepe gbese nii kojeki ìlọsíwájú wọ inú Aye wọn. Àmì buruku nii eleyi kaka kii wọn mura síi ọrọ Ayewon radarada nii wọn unba kiri
*Nje iwọ Mope ninu eyin Mefa tii iya ati baba yin kosi eniti odani ₦5000 ninu bank account ee bẹ sini gbogbó eyin Mefeefa bi wọn ba kọ gbogbo yin jọ ekole ríi ₦20000 tu jọ lati fii ran àwọn òbí yín lọwọ hummmm Ami buruku nii eleyi kodara.
*Nje iwọ mọ pé BODY ODOUR nii Ami buruku ti ayé gbé lé ee lọwọ
*Nje iwọ Mope Ọti mímú nii Àmì buruku ti ayé gbé lé lọwọ gbogbo awọn tii wonba fese lore òrun ọti yii konile je kii wọn ràn e lọwọ
*Mouth ODOUR nii ÀMÌ buruku to unja ẹlòmíràn
*Ọpọlọpọ awọn irankan àmi buruku arawọn nii Aini Aya iru awon yii ma ùn nii owó lọwọ gan ṣugbọn obinrin kii bawon kalẹ
*Ọpọlọpọ Akọbi Ọmọ nii Ami Buruku yii tiso di ẹni ẹyin
*Nje iwọ Mope Inú ilé bàbá ee tii òùngbẹ nii oun fa Ipọnju ati. Wàhálà sinu Aye ee.
*Nje iwọ Mope inu ilu baba ee owa nii olórí ogún ti ounja Ayé ee.
*Gbigba kadara odi gbọ olórí Ami buruku nii
Gbìyànjú kii Ose adura nii oru ògànjó kii omaba waye asa:
WAHALA ATI ADOJUKO IPO AKOBI OMO NINU EBII.
Opolopo Akobi omo oun sise bii Erin tii osi unjeje iliri kii olohun siju anuwo gbogbo Akobi omo
Besini opolopo obi nii otibaye Akobi ee je latara Oro enu.
Kodara kii awon obi feran omokan ju omokan lo ARISIKI tabi Ogo omo nii wonfii untafala nitoripe kosi eniti ofegbo pe Egbon awon fesorire ju owun lo tii Inu ee fedun sii
OKUNFA WAHALA SINU AYE AKOBI
*Kodara kii gbogbo Akobi maase Adehun pe ounfe segba see awo
*Kodara kii Akobi MAA binu abiju kii omaba pada dii enii yepere
* Kodara kii Akobi gbokan le ogun awon Obi kii omaba dii eniyepere
*Kodara koi akoba nii igbagbo ninu Adehun awon obi ee kii omapa pada dii ero eyin.
Nii OTITO gbogbo Ologo ati Asiwaju Omo ninu ebii nii oma un nii ogun sugbon kii olohun sinu Anu wo waaaa.
ÒGÚN TÍÌ NSỌ ÀWỌN AKỌBI DII ERO ẸYÌN*
Mogba ni Adura pe Gbogbo iwọ Akọbi nínú ilé yìí ọlọhun koni sọ rẹ di ẹrọ eyinì
Ọpọlọpọ akọbi loyeki otisẹ orire jubayi lọ ṣugbọn kádàrá rẹ tidi idakuda wonti la IGI AJÉ ilé wọn da ina.
Njẹ iwọ mọ pé tí osaba ma ùn ríi awọn Apẹrẹ mefa yìí Ogun idile ndá rẹ láàmú.
Bíi saba ma ùn fi oju, ẹsẹ, ará kò jankariwo yala loju ala tabi ojú ayé
Ìtumò:- Ifaseyin ati ijakule níí
Bíi obasaba ma ùn tọ sile (bed wet) níí ekan losu
Ìtumò:- wàhálà nifun iru akọbi yìí
Bíi obalala pe òun níí Ìbálòpọ̀ níí gbogbo igba loju ala lẹyìn náà ni owá bá Sperm nii Arare loju ayé
Ìtumò:- ogun ìdílé àti Ifaseyin, pelu Aya orun ni
Bíi promise and fail ba maunsaba wafun ee níí gbogbo Adawole ee
Ìtumò :-Ogun Akọbi níí kunfun adua
Bíi kobasi akojọ lẹnu iṣẹ rẹ tí odese iwadi síi tii osije ọna ọlá rẹ níí iṣẹ náà.
Ìtumò:- ogun Ifaseyin nii
ỌRINRIN àìsàn yìí ologo Akọbi ọmọ níí wọn má nfi daalamu nitoripe awon amokunseka kii nfẹ kii ògo aiye ee buyo
*Ìkìlọ*
Kodara kii akọbi ọmọ ma masturbate
Ìtumò:- níí Gbogbo igbati Oba nṣe Ikan won yìí awọn Aburu
Meta kankan amasele síi.
Koni síi iṣerere fún irú àwọn èèyàn náà
Koni leni Akojọ oun rere
Arawọn yóò maarun (body odour
DIE NINU AWON AKOBA TI OWA NINU OÚNJẸ OJU-ORUN
Nkan ibanuje nii ounjẹ oju orun je ọlọhun konije kii adi ẹni ẹyin
Ọpọlọpọ ẹda ènìyàn níí oun koju iṣoro yìí ṣugbọn ko mọ ọnà abayọ bíi oti lejepe orisirisii igbiyanju nii otise ẹlòmíràn tii na owó 💰 pa bo nii gbogbo ee ùn jasi
Púpọ ninu awọn alagbara aiye ma ùn fii òun jẹ jíjẹ loju orun fa wàhálà sinu aiye akọbi ọmọ kii won mase fii ẹni gíga ninu aiye bẹ sí í kii won mase ríi ogo wọn lo
Njẹ iwọ mọ pé OL'ogo ẹda ènìyàn níí oun ma ùn koju awọn iṣọrọ yìí.
Gẹgẹ bíi àpẹẹrẹ
Kii akọbi ọmọ máa tọ sile níí ekan tabi emeji kosi
Bíi kii wọn máa fi àìsàn WÁRÁPÁ dàn akọbi ọmọ wọ
Kii ẹnu mase to ọrọ láwùjọ
Ati bẹbẹ lọ.....
*EYINI AWỌN NKAN TI OUNJE OJU ORUN MA UN FÀ SINU AIYE ẸNI*
*OUNJE OJUORUN ma nsoni dii eni eyin nii gbogbo igba ọpọlọpọ ẹgbọn níí otidi àbúrò latara òun jíjẹ loju orun bíi ẹlòmíràn ba ùn sọrọ láwùjọ aiye koni Mope oun koju iṣoro nlánlá bayii
*OUNJE OJUORUN níí okunfa ikorira sínú aiye awa eda eniyan bíi ee koba mura síi ọrọ aiye ee odidandan kii ọna ati jẹ atomu bosi ìnira fún.
*Oúnjẹ oju-orun nii oluranlowo fún ọrinrin ati owu alantakun nitori pe bíi iku ilé koba pani tii ode kólé ráyè pàá ènìyàn.
*OUNJE OJUORUN ma ùn fa idamu sinu aiye ẹda eniyan nítorí pé níí gbogbo igba níí gbese ati oda owó má ùn da ẹlòmíràn láàmú latara oúnjẹ oju-orun
*Oúnjẹ oju-orun nii okunfa promise and fail púpọ ẹda ènìyàn níí oun koju amubo ọkọ àti aya nitori pe gbogbo igba níí wọn má ùn je ùn loju orun
*Oúnjẹ oju-orun nii okunfa opolopo Abiku òòrè sinu Aiye Eda eniyan ọjọ ti ẹlòmíràn ba ti níí àdéhùn pẹlu eniti yóò sọ sinu ìgbèkùn ojo naa níí yóò lalá pé òun jẹun loju orun.
*Ounje ojuorun kí ùn únjẹ́ kii opolopo Eda tete Debi tii oyeki ode ninu aye nítorí àṣeyọrí saba ma ùn jina síi iru wọn
*Oúnjẹ oju-orun orun níí okunfa wárápá sínú aiye ẹda eniyan oseese kii ọmọ jo'gun àìsàn yìí lọwọ àwọn òbí ee ṣugbọn latara oúnjẹ oju orun níí (báwo níí ẹda ṣẹlẹ bọ ninu wárápá)
*BAWONI ASELE BO LOWO OUNJE OJUORUN*
*Ṣọra fún àdéhùn sise pelu awọn ọrẹ ati mọlẹ bi
*Ṣọra fún wiwọ aṣọ ti otako irawo rẹ sun
*Ṣọra fún adisọkan lori adawole ee
*Máṣe sọrọ síi awọn agbalagba🦅
*Máṣe gba ogún ologun laye ninu aiye
*Ṣe àwárí ilé tí òun gbé kii otoko síi inu ile náà kii ùn se gbogbo ile níí a ungba.
Ṣugbọn yatọ síi iru awon nkan wọn yìí ọna wo gangan nii alegbe bọ lọwọ nkan burúkú yii???
ỌLỌHUN KONI FIWA SILẸ FUN AYEMU
*OKUNFA AMU BỌ ỌKỌ FUN OBÌNRIN*
Púpọ nínú obìnrin nii oun dojuko ìṣòro yìí ṣugbọn diẹ nii inu wọn nii komope kii unse oju lasan nitori ọnà mẹta ni Amubo ma ùn gba wa aiye obinrin besini bíi àkóbá tete mu ojuto lati igba èwe olewu fún ọmọ nii ọjọ ọla gẹgẹ bíi àpẹẹrẹ;
*LATI ỌWỌ ÒBÍ*
OJA ọmọ kìí ùn ṣe oun ti afii unnsere besini kainkain ọmọ tuntun kii unse òun ti alefi máa tafala nitori pe bíi Alaboyun ba tosí orí ọja ọmọ tuntun kosi Aniani odidandan kii ọmọ yìí nii amubo ọkọ nii ọjọ ọla besini bíi wọn bá mú ite ati kainkain tii afii ùn wẹ ọmọ tii wọn jọ papọ mọ ibi omo tii wọn tún lo da sinu odo tii oun sàn odidandan kii obinrin nii Amubo ọkọ
*AFOWOFA*
Ọnà keji nii afowofa fún arawa nitoripe kosi bíi osele wun ko ri to ọlọhun da ọkunrin fún obìnrin kodesi eniti owa laye tii koni ọkunrin ti ee ṣugbọn bíi ako ati igberaga bati poju fún obìnrin odidandan kii ofi ọkọ ṣe boy friends besini iru wọn má ùn nii ìdádúró lori nini ọkọ high taste loso OBÌNRIN miran di eniti ọkunrin ùn gbeju sile
Iwọ tii oun wa oni Benz's sugbon kìí sì nii ọkàn ee lati ba ọkunrin jeya kii ní aridaju pe oni Benz's yí óò fe óò gẹgẹ bíi aya púpọ nínú obìnrin nii oti fii akoko ee ṣofo ṣugbọn komo.
*BII EDA BATI SII ESEGBE NII OWURO KUTUKUTU AIYE EE.*
Opolopo Eda nii otisife nigba ewe ee tii wonti fii AMII sii Lara eleyii amajeki awon eyan magbe jusile kii unse pe Awon aye fii Seka fun biki basepe oti tii sii ESEGBE Sugbon bii olohun bafese Anu ee odidandan kii opade eniti yio ran lowo kuro ninu isoro bayii.
*KAINKAIN OMO TUNTUN* *ATI ITE OMOTUNTUN*
Opo Obi nii wonti fii Owo wan fa Amubo OKO TABI AYA sinu Aye omo won latara Fifi Inu tan ore friends nitoripe kodara kii amafi KAINKAIN tii afiwe omo ikoko tabi ITE OMOTUNTUN tafala nitoripe won ma fii unse ISE IKORIRA SINU AYE EDA ENIYAN Eni BII aye bada ikorira sii EYAN Lara odidandan kii oma mu Amubo kosi boseleni Owo 💴 lowo to koniri oko tabi Aya tii yio fedi ojo Ale nitoripe wonti lo owun AMUSE AGBARA REE NIGBE IKOKO OOO.
*EPE LATENU OBI*
Pupo ninu obi nii oti fii enu Baye omo reje latara epe sise
Gbogbo awon nkan wonyii kodara bii epe batibere sini jaa omo odidandan kii ikorira wonu iru Aye enibe Osile faa Amubo pelu.
BONUS
Ti o ba la ala wipe O nba obirin sun loju orun ti sperm wa da jade ti a rare si wet,
ITUMO;- IFASEYIN IJAKUNLE PROMISE AND Fail nii iru ikan bayii manfa sinu aye Eda ...Adua ati Ise awon igbiyanju lafinsegun nkan bayi tori ise awon ota niyen
Ti o ba la ala wipe o ba afesona re lopo loju orun
ITUMO:- Eo le fe arayin lailai o si gbodo fi agidi fe iru Obinrin be o lewu fun e mura si Adua daada ki o le ri Obinrin gidi
Ti o ba la ala wipe onigunnu nba e ja loju orun
ITUMO:- Ise awon ota inu ebi re ni mura si adua kiwon maba bori e
Ti o ba la ala pe o fi umbrella ☔ bori loju orun
ITUMO:- Wari bibo asiri ati anu lodo Olohun mura si adua daada
MOGBALADURA PE AMUBO KONIJE TII EMI ATI IWO.
OOGUN TI OLE BA JI NKAN WA LO*
Ori alakedun,
ata ijosin 9,
ewe Ina,
ewe esisi,
ewe aragba,
ewe oloyin,
ao lo awon ewe yipo
mo ose,
Ao fi di oju alakedun kan,
ao lo ata ijosi pelu omi die ao je koki ao fi di ojukeji...
Aofi igi kan gun nidi aogbe duro looro sigun yara...
Ao wa eyo igbale mesan to gun dada eyiti won tifi gbaleri aodi bi osusu owo ao naro re si legbe.
OFORE: (ao ma je eyo atare mesan lenu, ao si tun mofi igbale ti adi yen malualakedun yen lori) Pelu sisope....
Afataboju kirojusoju, afoseboju kirojusoju, okualakedun kiroju jagbado, kankankan lewe inajo, warawara lomode toko esisi bo, ileogbaona o gba nise ewe aragba, ewe oloyin kipahun obarisaa da..... Enito gbe hun bayi
(aodaruko hunkan tiwon jilo yi) ki ile mogba ki ona magba.... Ayafi kowa dapada..... Ao wa
tu atare tan je lenu si ori alakedun yen.....
NOTE: ojo meta Pere ni ama fi se ise yen, onitohun maa daa pada.
OBINRIN
Pataki nii gbogbo awon obinrin he ninu aye AWA Eda bii okunrin bawa tii kosi obinrin ninu aye ee oseese kii odi Eni yepere lawujo.
Nje Iwo mo wipe ISUBU EE Loni Owo obinrin lotiwa
Okunrin meji lowa ninu Aye gege bii Apere;
OLOKUN ESIN/ FAWORAJA
OLOKUN ESIN je okunrin Tii Oni Ori obinrin pupo ninu won je AFINJU besini die ninu won je Akinkanju omiran ninu won lema rewa( None Hanshome ) elomiran ninu won sile rewa( Handsome) besini obinrin ma npo funwon gan wonsije ONISINA Eda kosi Sugbon isubu won Owo obinrin lowa besini ORIRE WON Owo obinrin lowa pelu.
*AKIYESI*
*kii unse gbogbo obinrin nii eyan legun AYA EE oseese kii OSII. Ta okunrin Tii obagun Ori obinrin imiran
*Kii nse GBOGBO obinrin tii obagbe OWO IFE wa nii ama nbasun kii aye ee Mase Baje
*Kii unse gbogbo obinrin naa nii wonti lo Sugbon bii obaje emere elekisa oseese kii okunrin gun AYA EE kii aye okunrin naa Baje.
*OKUNRIN ALAJE*
IRU awon edabayii ma un nii OWO 💵 lowo gan Amo latara obinrin nii wonti nii owo gege bii eniti ofe ELERE OMO Sugbon ojoti obati lu ( fight ) with iyawo ojo yen nii OGO Aiye ee Titan
Iruwon awon Okunrin bayii kii unsaba nii Ori obinrin bii wonba ko enu Ife sii obinrin awon Obinrin kii nfibe GBA funwon pupo ninu won nii Ayawon ma unja lati ba obinrin soro besini won nifesi MASTURBATE IKAN wonyii ma unle OORE ATI OLA kiro nii arawon nii
Sugbon kosibi osele rito ALAJE obinrin nii won ma nri Fe gege bii iyawo besini leyin tii wonbati nii owo tan won ma nfe iyawo keji
EYIN EYAN MI LOKUNRIN EJEKI AGBADURA KII AYEWA MASE BAJE
BESINI KII AWANA SORA FUN IWA ELEGBIN ATI AGBERE.
No comments:
Post a Comment