Monday, June 20, 2022

ỌRỌ NÍPA ORI BIBO 💯

               ỌRỌ NÍPA ORI BIBO 💯 

Ori jẹ ùn kan pataki lati máa bọ bẹ síni ilọsiwaju wà fún gbogbo ẹnití òun bọ ori ee 
Kii ùn se gbogbo eyan níí nkan dudu tabi ogun ùn sise níí ara wọn nítorí pé gbogbo irawo kánkan ni oni nkan ti oba lara mu 
Njẹ iwọ mọ pé bíi nkan wọnyii ba ùn ṣẹlẹ sí ee odidandan kii o bọ òrí rẹ nítorí pé igbiyanju nii òun mu eni gaa láyé gẹgẹ bíi àpẹẹrẹ
Bíi iṣẹ ko ba lọ dédé
Bíi gbese ba pọju fún ẹdá ènìyàn
Bíi idiwọ ọmọ bíbí ba ùn da eda ènìyàn láàmú
Bii alakala ba ùn pọju fún ẹdá ènìyàn
Bíi ipọnju ati IFASEHIN ba ùn ṣẹlẹ síi ẹni
Bíi kobasi ifọkanbalẹ lẹnu iṣẹ tabi níí idile ẹni
Bíi ogun ìdílé ba ùn da eday ènìyàn láàmú
Bíi èpè ba ùn jani
Bíi ẹda ko níí àṣeyọrí lori adawole ee 
Ọpọlọpọ ẹda ùn sise bíi ẹrin tii osi ùn jeje eleri ṣugbọn niwonba ìgbà tí obati bọ òrí é 
Ọpọlọpọ ẹda eniyan níí ko mọ pé ori òun níí oun takò owun lẹnu iṣẹ idi niyi tii kofi síi akojọ fún 
Púpọ ẹda nii oun gbé ìlú ti otako ori ee ṣugbọn anfani tii koni lati bo ori òun l'ofa wahala síi inú àiyé ee Logan tii obati bọ òrí odidandan kii eleda ee tètè lánàá fún 
Òwu alantakun 🕸️ tii fa ijakule sinu aiye ẹlòmíràn ṣugbọn logan tii obati bọ òrí ee odidandan kii wahala kuro ninu aiye ee 

                         ÌKÌLỌ
kii ùn se gbogbo eyan níí olebawa bọ ori wa 
Bíi ẹda koba bọ ori ee ni ona tii o to wahala ati ma wọ inú àiyé ee 
Bíi ẹda koba bọ ori níí ilana rere ijakule atun ma wọ aiye ee
Gbogbo eniti o bọ ori ee gbọdọ jẹ ninu  nkan ti won ba fi bọ ori yala 
Ẹja aro 🐟 gbigbe tabi tutu
Ṣugbọn ọmọ omi kogbodo je eja aro 🐟
Adìyẹ 
Ẹyẹ 🐦 ẹtù
Ewúrẹ 🐐
Ìgbín 🐌 ṣugbọn onirawo erupe kogbodo jẹ ìgbín
Obi 
Orógbó
Ati bẹbẹ lọ



   

No comments:

Post a Comment

CONNECTION CLIENT SOAP GEE BOY 💯

 CONNECTION CLIENT SOAP GEE BOY 💯  Ewe Omisinmisin ti amo si eso oju Olohungbo Oojo tuntun die,ao fo Odidi eyin Ororo ibile ti o mo dada 1k...