AWỌN NKAN TI OTAKO GBOGBO IRAWO FUN ỌJỌ IBÍ NI ṢIṢE 💯
Ọpọlọpọ níí ohùn se nkan tii otako irawo ee bẹ sini kii ùn se pe o mọọmọ se nkan won yii a mọ Aini imo lori nkan tii irawo wọn ko fẹ níí okun fa nkan wọn yìí
Aiyimoye eda níí o jẹ gbese tabi níí o wọ wahala leyin BIRTHDAY ti o ṣe nítorí pé òun ṣe nkan tii otako ipin iseda irawo ee ni
Gẹgẹ bí àpẹẹrẹ.
IRAWỌ AFẸFẸ
Níí gbogbo ọjọ ti irawo yìí bá fẹ ṣe birthday eyinì nkan tii kogbodo ṣe
Ṣọra fún ìjà
Mase jeki won da erupẹ síi ee
Ṣọra fún Ibalopọ níí ọjọ yìí.
Ṣọra fún àdéhùn sise níí ọjọ yìí.
IRAWO INA
MONDAY
Omo TII ojo ibire baabo Sii ojoyi kii igbiyanju LATI Mase
Mu oti ( alcoholic)
mase jeki enikeni gba EE nii ORI
NI suru nii ojo yii kii ojo ale ATI ojo Ola ee lebosi irorun
nii ojo yii nitoripe Ifaseyin ojo ola NI ikanyi nfa.
TUESDAY
Mase would Aso dudu nii ojoyii kii wahala Mase wonu. Aiye. EE.
WEDNESDAY
Mase baa obinrin tabi OKUNRIN nii IBALOPO SEX nii ojoyii kii igbiyanju le sise ninu Aiye EE.
THURSDAY
FRIDAY
MASE jeki wonda Omi Sii EE Lara kii wahala Mase SELE nii ojo yii
SATURDAY
SUNDAY
ojo yii nii Agbara gan fun iwo tii ojo ibire baabo sii ayajo yii tii otunje onirawo Ina
Mase gbiyanju LATI wo Aso pupa ATI fila pupa ounti odara ju fun EE Niki ogba Awe kii osimase gba enikeni laye LATI daa Omi Sii EE Lara notoripe iseda ree takoawom ikan wonyii.
IRAWO OMI
MONDAY
WEDNESDAY
Iwo tii ojo ibire baabo Sii ojoyii Mase daaba LATI pariwo Arare besini Mase gbiyanju LATI wo Aso dudu ATI Aso yellow eleyii tako iseda IRAWO EE besini kii omu inu OPOLOPO Eda eniyan dun nii ojo yii sugbon iseda ree kofeki oba enikeni jaa ( fa wahala ) nii ojo ibi ree ku ojometa kii Ifaseyin Mase wo inu aye EE.
THURSDAY
FRIDAY
SUNDAY
Oun tii oje ibanuje Nipe eniti oje onirawo omi ti ojo ibire bosi inu Awon ojo yii gba kii won da Omi idoti Sii owun NI ara Gbogbo eniti obase ikan wonyii yio fa Ifaseyin ATI Akoba fun iru OKUNRIN tabi OBINRIN tii ojo ibi EE bosi inu Awon ojo yii pelu afikun EYINI AWON ikan tii odara kii eniti ojo ibi re bosi Awon ojo yii Mase kii idunu lewo inu ayewon.
Gbiyanju kii ogba Awe nii ojo yii.
Mase jeki enikeni gba ee nii Ori.
Mase lo Ata nii ojo yii.
Gbiyanju kii owo Aso FUNFUN nii ojoyii besini Mase binu nii ayajo yii kii wahala Mase SELE.
SATURDAY
GBOGBO onirawo omi ti ojo ibire baabo Sii ojoyii kii onitoun gbiyanju LATI pe apeje fun Awon agbalagba ATI Alabagbe EE kii ofi IYO (SALT) SE SAARA nii owuro kutukutu kii wonto bere eto.
IRAWO ERUPE
Kose maani nii Awon IRAWO yii je kosi owun tii wonkole see Gbogbo ojo ti birthday won baabo Sii sugbon kan soso nii otako iseda won
Wonkogbodo fii enu kan IYO ( SALT ) nii ojo yii kii oun Gbogbo lema lo Deede funwon .
Ògún ologun koni jẹ tiwa lagbara ọlọhun
Ọlọrun koni jeki afi ọwọ ara wa se ara wa
Ki Olorun siju anu wo gbogbo wa
GBIYANJU KO NI IWE
ASIRI IRAWO EDA LOWO
GBÌYÀNJÚ LATI SE ÀWÁRÍ ARA-RE KII OMABA WÁYÉ ASÁN
No comments:
Post a Comment