ÌLÚ TÀBÍ ÀDÚGBÒ GBÍGBÉ FUN GBOGBO IRAWỌ 💯
Odara kii amò ilu tabi agbegbe ti odara fún ipin ati iseda irawo wa nitori kii amaba waye bíi aláìsí bẹ sini kii amaba di ẹni ẹyin kii ùn se gbogbo ikan náà níí ota fii ùn dáwà láàmú besini kii ùn se gbogbo ikan níí ogun ìdílé
Ejeki amo ilu ti odara fún ipin irawo wa gẹgẹ bíi àpẹẹrẹ;
IBUGBE IRAWO INA
Ejeki abere Lori irawo ina pupo ninu awon iseda yii Agaga awontii wonbii nii Ojo Monday orowon kii unduro lojukan pupo ninu won je Akiikanju wonsi ma ungba ero ikan nlala.
ILU TI WỌN LÈ GBÉ
Odara kii wọn magbe ilu tabi agbegbe ti Oke posi (mountain) wọn tún lẹgbẹ ilu tabi Adugbo tii Afefe waa daada kii wongbiyanju lati jekii igi wanii Ile tiwonba Kọ fún arawọn nitoripe Afefe aleje oluran lowo fun wọn
PẸLU ÀFIKÚN
Iseda won ikan giga giga nii wọn má ungba lero ju
Iseda yii saba má ùn ló ikan pupa sugbon wonkii un mọ elomiran ninu won ma un mu Oti kii unse ebiwon bikii se iseda irawo won.
IBUGBE IRAWO AFEFE
Oba irawo nii irawo yii je kosi ibiti kole gbe won feran latii maase ibere daada wonsi je eyankan tii oma ùn beru pupo ninu won kii un sábà ma un gbagbo pe eyankan wanii idi Oro won nitoripe isada won nii Agbara gan wonje oloju Anu
Bii wonba unparo Ifaseyin die die ama waye funwon
ÌLÚ TÍ TIWONLEGBE
Iseda yii koferan Oru, beeni Wonko feran idoti
Kosi ilu tii Afefe kolegbe sugbon odara kii irawo yii maa gbe ilu tabi Adugbo tii Omi posi. Daada.
IBUGBE IRAWO OMI
Kosi Eda Alaye tii oleba irawo yii see ota nitori pataki wonpo lawujo
ÌLÚ TÍ TIWONLEGBE
Odara fun irawo yii komagbe Adugbo tii Omi tabi Alafia ma nwa daada nitoripe Omi kii unse ota eyankankan bii Oni irawo Omi ba ungbe ilu tabi Adugbo tii Omi tabi Alafia ba ùn wa odidandan kii irawo ati Ogo ee matesiwaju
Diẹ ninu awọn onirawo yii elegbe niwon egbe bii.
Omo Omi
Emere Omi
Iranse Aje
Alaragbo
Ati Bebe lo.
IBUGBE IRAWO ERUPE
Odarakii irawo yii magbe ibiti Ero baapo daada nitoripe kosi eniti olemo iwa iru irawo yii tan
Irawo yìí féràn ilu ti tabi agbegbe ti kii ba ùn da nítorí pé kii ògo ati arisiki ee lè tètè tẹ lọwọ
Die Lara awon Obinrin irawo yii Je elegbe bii
Iranse Àjé
Igi Aje
Omi Anu
Omi àjé
ÌLÚ TÍ TIWONLEGBE
Ilu tabi Adugbo tii awon eyan ba Saba maun posi nii odaraju fun irawo won nitori pe àjé kii ùn fẹ kii gbogbo agbegbe tí òun bawa ba dull.
Pẹlu pẹlú àwọn tí wọn ùn ló ipin iseda irawo erupe funfun
Fun Amonran Lori Irawo eda ABI Lati mo Irawo Re
No comments:
Post a Comment