AWON AWO(COLOR) TODARA FUN IRAWO KOOKAN 💯
Odara fun irawo kookan komo iru aawo toba irawo remu nitori ose koko si igbesi aye wa gegebi aso wiwo, tabi oda ikunle ati awon nkan Miran
IRAWO OMI
1_FUNFUN
2_GREEN
3_OMI ARO
IRAWO INA
1_ASO PUPA
2_GOLDEN COLOR
3_GREEN TABI YELLOW
IRAWO IYEPE
1_BROWN
2_GREEN
3_PURPLE
4_RED/CREAM
IRAWO AFEFE
1_ASH
2_YELLOW
3_WHITE
4_PURPLE
Odara ki Olukaluku mo nipa irawo re papa julo nipa aso wiwo, eewo,Sara,ojo orire,asiko gbigba adua pelu awon nkan Miran toba irawo re mu nitori ki nkan lema lo Dede fun e ninu aye opolopo loti kosi inu wahala nitori wipe ounse nkan tioba irawo remu
Asima nko sinu wahala lati ara aso ibora nitori osaba man fa ala buruku ti yio siko elomiran sinu wahala
Ema bami kalo
OKUNFA ALA BURUKU ATI ALAKALA NIPA ASO WIWO SUN FUN GBOGBO IRAWO
1. IRAWO AFEFE. kodara ki irawo yi mawo aso aso pupa (red),alawo ewe(green),tiwon bafesun lale. Aso todara ju fun irawo yi lati mawosun ni ASO FUNFUN
2. IRAWO INA. kodara ki irawo yi mawo aso tobati lagun si sun (sweat),aso toba doti(dirty)sun,aso toba fi se ise (working cloth),kodara kiwon mawo aso alarabanra sun
3. IRAWO IYEPE. awon aso tikodara fun irawo yi lati mawo sun ni aso dudu,aso brown,aso tiwon fi ni ibalopo,aso okunkun
4. IRAWO OMI. kodara ki irawo yi mawo aso Ankara sun,aso yellow,aso dudu
Kise gbogbo alakala lowaye lati owo ota,aso wiwo sun tabi bibora manfa alakala fun onirawo kookan
Ọlọrun koni jeki afi ọwọ ara wa se ara wa
Ki Olorun siju anu wo gbogbo wa
GBIYANJU KO NI IWE
ASIRI IRAWO EDA LOWO
GBÌYÀNJÚ LATI SE ÀWÁRÍ ARA-RE KII OMABA WÁYÉ ASÁN
No comments:
Post a Comment