AWON AKANSE ETO AGBARA TODAJU π―
ETO IFE OKUNRIN ATI OBINRIN
Alubosa Nla Funfun Kan
Paper Funfun die
Iyo Didi Die
Odo ti kigbe(River)
Ao ko Oruko Ololufe Mejeji sinu paper Funfun yi ti ko ni Oruko Iya won ninu(Mother name Requires)ao tibo inu Alubosa,ao fi Iyo die si,ao we ni Owu dudu ati funfun ti ko ni han mo,ao lo ri mole si egbe Odo ti kigbe Opari
Ise yi daju pupo,eni ti aba se ise yi fun,kole fi wa sile rara,Sugbo e je ka beru Olorun,Nitori awa Okunrin Oloju komo lo
IFE TODAJU
Ao fi abere gun atanpako owo wa ao te eje re jade
Ao wa fi ko oruko MALAIKA Yi (RAMPEL) Si Ara eyin adie ibile pelu oruko obirin yen
Ti a ba tise eyin jina ni ooo A o pe oruko yi nigba meje si eyin adie yi pelu adura iferan Odaju...obirin na koni fi o sile mo lailai.
Akiyesi:-mase ise yi fun obirin ti o ko ni fe sile ooo
ISEGUN OTA
Ti o Bari pe ota kan gbogun tio...gbawe ojo kan ki o ka psalm 10 nigba meje Oruko Malaika nigba meje JARATA AJAJAMOMIN
Ao ka ni aro,osan,ati ale Odaju ao segun awon ota na
OJURERE ATI ANU
Ao fi omi agbon gbo ewe rerinkomi ati ewe owu akese
Ao wa da sinu CREAM JET
ao tan abela bulu (blue candle) sidi re ao pe oruko mimo yi si ELI LAHA BAHA
pelu psalm 19 nigba meje si Ao fi abela na sile KO joku odaju...a o ma fi para
ISEGUN ALAROKA
Ao ka psalm 3,35,22,109
Sinu omi iwe
Ao gbawe ojo kan se adura yi Ao wa lo fi omi na we...alaroka yoo tuka
ISEGUN ADITE TOLAGBARA
Ao wa ka psalm 46, 109, Isaiah 47 ao ka ni osan gangan ni ago kan tabi oru
Ao wa ma da oruko awon Ota re si.. Olorun yoo na won legbe
ASIRI BIBO
Ao ma pe oruko mimo Yi nigba 70times Lojumo ELOHIM Odaju asiri wa yoo bo
ISEGUN EJO KOTU
Ao ma pe oruko mimo Yi nigba 71times
JAJI JAILA AKABAJAH
Ao si ri ojurere awon adajo Odaju ooo
Mafi oju di eto won yi oo
IFERAN ARAYE
Ao ma pe oruko mimo yi Nigba meje sinu perfume eyikeyi...wa ri bi ojo ife yoo se ro le o Lori JANTALIKOKO ELI HAL 7times ao wa ka psalm 24 si nigba kan 1 sinu odaju pa
ISEGUN ALAKALA
igba idemu
Ao bu omi sinu re
Ao ka psalm 7 7times A o wa gbe si iri moju,A o lo gbe omi yi ni idaji laisoro si enikeni ao wa gbemu. odaju koni si alakala mo.
ABO OLORUN
ao pe oruko mimo yi
Nigba meta pere
ELOI ELOI ELOI
ao wa ka psalm 20 nigbaMeta ni Dede ago mejila osan Ao ma se ni ekan lose
IBUKUN TODAJU
Ti oda owo money
Ba da eyan Gbiyanju Ase oro yi
JEHOVAH SHALLOH
JEHOVAH JIREH
ADONIS JEHOVAH
SALLAH JEHOVAH
NUN-JAH-SANATH
ITAMI-SELLAH
ELEYI NI ASIRI IMULE ARINURODE AWON AGBALAGBA TODAJU
Egbo tude idi meje, Aidan onigun meje, Omo olongbo ti koiti laju,Odidi atare meta,Epo obo topo dada, Akuko adie kan,Igba onikoko, Opon ifa ti wonfi igi iroko gben,Ape ijoogun tuntun,Seere nla kan,
Ose dudu, Eso laa mejeji oojo,Ewe ajeobale oojo,Ao pa olongbo yen,ao wa fi eweajeobale tele ape,ao gbe olongbo naa lee lori ao ko egbo tude si ao ko Aidan si ao ko
atare meta yen si ao ko epo obo topo si ao pa pepe kato kosi,ao ko eso laa mejeji si ao tun wafi ewe ajeobale boo lori dada pada. Ao fi epo pupa yi aro kaa, ao jo,tia ba jotan ao lo kunna dada,ao wa da ebu na sori opon ifa ao fi te odu ifa merindinlogun si, ao daniyan ohun ti abafe si. Ao pin si ona meta ao po ida kan mo ose dudu ao ko sinu igba,onikoko yen. a o wa pa Akuko Adie kan togbo dada ao roo eje re sinu ose yen,ao fi owo po papo,ao da ebu ona meji toseku papo ao ro sinu ado seere yen ao fi eje adie toseku yen boo seere yen ao le iye igbaaya re mo seere yen Lara,ao gbe
Igba ose yen ati ebu inu seere yen sinu aso funfun otooto. Ao gbe sinu apoti tabi cupboard wa tori oju meji kogbodo rimon,ao gbe pamo fun ojo meje,lehin naa ao wa se sarare,ao ma fi akara elepo pupa tabi ekuru funfun see saara re lojojumo fun ojo meje yen lehin ojo keje ao bere lilore.
LILO RE
Ao ma fi ose yen we lalale ti agogo mewa bati koja, Ao ma fi ebu inu seere naa fo eko tutu mu larolaro
kato soro si enikeni
NOTE
Obinrin kogbodo loo imule yio,toripe oni ewu fun obinrin ooo.
Ise gidi ni ise osi daju dada moti gbiyanju re laimoye. Kosi nti amu waye losi nti amu lo orun.
LILO EWE EWURO FUN ISE/OSE ANU NI ORISIRISI ONA TOSI CONFIRM GIDI 100%
ISE ANU.
Ewe ewuro oojo ao gun mose dudu ao fi epo pupa,iyo ati oyin po,ao ko sinu fitila oloju kan ao ti abela funfun kan bo larin ao ma tan ina si ti a ba ti fe lo we ose na,ao ma fi owo pa ina leyin iwe
ISE ANU.
Omundun ewe ewuro oojo, ewe ola, epo obo, kafura pelebe packet kan, ose dudu, ao da osun, oyin ati ori mo omi agbon ao fi po ose na, ao ko sinu ike funfun wiwe laro
Omundun ewe ewuro ojoo, kanfura pelebe packet meta,ao gun mejeji papo mo ose dudu ao ko sinu ike funfun wiwe laro.
ISE ANU.
A o fi ori olongbo ti o ni irun tele ape,a o da Ata ijosi le Lori,a o fi ewe ewuro oojo bo mole,a o fi atare kan le Lori,a o Jo,a o ma fi epo pupa la le,a o ma fi oti lo laro. Gbogbo awon ise yi daju gidi walai
No comments:
Post a Comment