ETO AWORO ALANU FUN WOLI,ALFA,TABI ONISE OWO 💯
Ise Nare. Ajesi Orun Adie Ibile toni Agbado ninu kan,Ewe Anu die,Ewe Sawerepepe die,Ewe Atewogbare die,Eru Alamo die
Sise Re. Ao lo gbobo re pomo arawon,ao pomo Ose Eyikeyi ti o ba wu wa,ao ko Ose na sinu ikoko Ajere,ao mafiwe lararo pelu.
Psalm Re. Ojojumo ni Ajesi adiye mangba alejo ki Emi L.Omo L. gbalejo Olowo loni,Sawerepepe lobami pe Olore ati alanu mu wa loni,Ewe Atewogba loni kintwo migba Owo Nlanla loni,Eru lobamiru won wa towotowo Owo(hand)won,Ona kona lomi ngba wonu Ajere,Ona kona nikingba ri alanu tiyi ofi Owo Nlanla sanu mi loni
ASEJE BASIRI OWO
ewe rinrin oojo,panmo dudu tagesi 16,iru Pete,iyere 16,ata ijosi 16,ikoko aseje titun,epo,iyo,
SISERE. ao fi omi san ewe yen nu Tori erupe ara re,ao fi sile ki omi arare yen gbe,ao lo iyere ati ata yen po,ao wa ko ponmo yen sinu isasun,ao wa da ata ati iyere talo lelori,ao tun da iru si,ao wa gbo ewe yen laifomi si rara,Omi tojade lara ewe yen ao da sori ponmo yen ao se lepo niyo,ao so sori osuka aso funfun,ao se adura si ao je,ise yi yara mu owo wa kiakia,ejeka gbiyan jue wo
No comments:
Post a Comment