ÀLÁ LILA ÀTI ÌTUMỌ 💯
Oludamọran fún ọrọ aiye wa níí ala lila jẹ bẹ sini bíi eda koba mura síi ọrọ aiye oseese kii owa bakanna
Bíi obalala pe oun Lu Agogo níí ojú ala tii agogo yẹn kọwa dun sita
Ìtumọ:- igbiyanju Onitoun ko ti to kii onitoun tẹra mọ adua
Sugbon bíi Agogo náà baa dún jade
Ìtumọ:- Onitoun yóò gbo iroyin ayọ laipe
Bíi eyan ba ríi ọmọ ọlọ níí ojú ala
Ìtumọ:- Onitoun yóò ṣe àṣeyọrí lori Adawole
Bíi obalala pe oun gbe ọmọ pọn loju ala.
Ìtumọ:- gbàdúrà kii omase ríi idamu.
Bíi oba ùn wẹ fún ọmọ loju àlá tii o de síi in w'oju Olohun fún ọmọ
Ìtumọ:- kii onitoun gbàdúrà kii ati bimo mase jẹ ìnira
Bíi obalala pe won fún ee níí bundle owó 💰 níí oju ala.
Ìtumọ:- wa ríi oda owó tẹra mọ adua
Bíi ọmọ ìkókó naya ìgbé síi ee lára níí ojú ala.
Ìtumọ:- wa ríi idunnu tabi kii ori nkan ayọ laipe
Bíi obalala pe oun se weeding níí ojú ala níí gbogbo igba
Ìtumọ:- gbàdúrà ọkọ orun tabi aya orun mase da irin ajo aiye ee ru.
Bíi owa wa ninu ojo loju ala
Ìtumọ:- idaamu níí kún fún adua
Bíi obalala pe oun gbo Radio 📻 loju àlá
Ìtumọ:- wa gbọ ìròyìn ayọ laipe kún fún adua
Bíi obalala pe oun jẹ ọgẹdẹ 🍌 loju ala
Ìtumọ:- wa ríi nkan iderun
Bíi obalala pe ina 🔥 jo gbogbo nkan ini ee loju ala
Ìtumọ:- gbàdúrà kii omase padanu nkan tii ogbè ọkan lè
Bíi obalala pe phone ee sonu loju ala
Ìtumọ:- connection rere nla yóò bọ sonu kuro níí ọwọ ee
Bíi obalala pe oun jẹ akara loju
Ìtumọ:- awọn agbalagba 🦅 yóò mú ifaseyin ba ee
Bí obalala pe owa ninu ọja owa fẹ ra ẹran tutu
Ìtumọ:- ṣọra kii omaba fii ọwọ arare fa ifasehin sinu aiye ee .
Bíi obalala níí gbogbo igba pe owa níí ìhoho loju
Ìtumọ:- asiri Onitoun koni bọ kún fún adua
Bíi obalala pe ọrẹ gba bàtà níí ẹsẹ ee loju ala
Ìtumọ:- nkan lara awon ọrẹ ee yo gba ololufẹ mọ ee lọwọ.
Bíi oba wọ aṣọ pupa loju ala
Ìtumọ:- ìṣẹgun wa fún ee kunfun adua
Bíi obalala pe won fún ee níí ounjẹ jẹ nii party tii Iwọ náà síi jẹ
Ìtumọ:- lara awon tii osunmo yóò sọ ee dii ẹni ẹyin
Bíi obalala pe won síi fila kuro níí ori ee tabi Ose fila kuro lori eniyan
Ìtumọ:- gbàdúrà kii won mase gba ogo aiye ee danu
Bíi obalala pe owa ninu Motor Motor yen wa ùn pada seyin.
Ìtumọ:- hummmmm gbàdúrà kii omase ríi àpadà síi aburu
Bíi obalala pe owa pẹlu awọn ile friend tii Iwọ ati won jọ se kékeré loju àlá
Ìtumọ:- ikolo re yóò padà besini gbàdúrà kii ọta mase sọ ee dii ẹni ẹyin.
Bíi obalala pe oun gbon òwu alantakun 🕸️ loju àlá
Ìtumọ:- eleda ee tii n ba ṣẹgun ijakule
Mogbadura fún gbogbo ẹyin témi pe Aiye koni fii ogo wa rare
Ọlọrun koni jeki afi ọwọ ara wa se ara wa
Ki Olorun siju anu wo gbogbo wa
GBIYANJU KO NI IWE
ASIRI IRAWO EDA LOWO
GBÌYÀNJÚ LATI SE ÀWÁRÍ ARA-RE KII OMABA WÁYÉ ASÁN
No comments:
Post a Comment