OSE BIBO ASIRI TODAJU SAKA 💯
Isena re
👉Efo gure.
Ose lux tabi joy meji (2).
Kafura pelebe. Idi kan.
👉Sise re. Ao han gbogbo ewe efo gure yen laisi igi tabi ododo kankan nibe ao gun po mo ose lux tabi joy meji,ao ko sinu ike funfun Olomori. Ao wa gun kafura pelebe idikan loto. Ti aba ti gun kafura yen tan ao wa kosi lori,ao wa fi owo(hand)wa ropo daada
👉Lilo re ao ma fi we laaro kutuhai.
Odaju gan ni o
AROBI/ASETA
ao fi iso tuntun lu oju agbon kan,a o wa ko omo atare 42 si enu a o je kuna,a o mu omi agbon yen si pelu adura pe gbogbo eni toban dimi lowo ise rere ki oro re o dojuru,ti aba mu omi tan,ao fo agbon danu.
OSE AWURE/ITAJA
Ewe ominsinminsin gogoro, ewe abamonda,oga aye kan, ikode 3,ao gun gbogbo re papo ti yio kunna daada,ao fi ose poo, ao wa fi lofinda bintu kan po ose naa,a mafiwe larolaro.
IFERAN OBINRIN CUSTOMERS OBINRIN
Ileke segi,efun, osu,Ileke tun, Ileke ifa,ao gun po,ao da sinu lofinda. Ao mafi pa oju ati owo, ara.
AWEBI WEPE DANU
Ao lo wa epo obo die ao gun mo ose dudu pelu ewe bomubomu ao lo fi we lodo lekan soso.
TURARI ITUWO TO DAJU
Ewe ajekobale,igi oro onigege, epo obo,a o gun po,a o wa sa,ti o ba gbe tan,a o wa ma fi fi turari sile wa ni aro ati ale.
ISEGUN IKORIRA ATI IFERAN
Ao ka psalm 150, 71, 7times,sinu omi agbon,ati igo bintu kan pelu awe ojo kan ao wa mix omi agbon ati bintu papo. ao ma kan sinu omi iwe,ati ipara. odaju awon eniyan yoo ma feran wa...ikorira yoo si dagbere fun ooo
OGUN INANRUN TODAJU
Egbo gbogbonse,egbo ipeta,egbo ifon,egbo agbasa,egbo legunoko,egbo tude,egbo inabiri,eepo konunkoho,eepo igi opele,baaka,alubosa elewe,isu alubosa,ata wewe pupa,imi ojo dudu,atare16,kanhun,fofo okun,iyere,jankaawo,eeruawola,aidan tio ba ni isu daadaa,ao gun gbogbo repo,ao maa fi mun eko gbigbona
BI OLE BA JI INKAN WA
Ogun to ole ba ji nkan wa a o wa obi alawe meta 2 a o fi gbadura ki ole ti o ji nkan wa yen da pada atipe ki asiri re ko tu dandan a o wa lo fi obi naa ta awon alagbe lore(ikan fun alagbe okunrin ikan fun alagbe obirin) loba pari odaju pe asiri ole na yoo tu tested work ni o
OGUN OKIKI
Akere tio pe, akuko adie kan,eye owiwi kan ,ori akuko ati ori owiwi,ati akere ni ao lopo tiyio kunna dada ao pomo ose dudu,ao mafiwe.
Ofore. Mawi mawi nise eye owiwi,owiwi loni ki won mawi mi kaye (Aniyan),Toripe akere nijuwe ibiti odo wa (Aniyan),akuko nijuwe Ilu ki omoaraye majuwe mi si dada. Ao mafi ose na we
No comments:
Post a Comment