Friday, January 6, 2023

SOLUTION SI OWU ALANTAKUN πŸ’―

 SOLUTION SI OWU ALANTAKUN πŸ’― 


AKIYESI PATAKI:- Opolopo ni OWU ALANTAKUN Aiye ti ta Okun dina fun Eleda re, Sugbon O nso wi pe, Ori ko fo Oun, Saka lara Oun le. Opolopo Eeyan lo nbe Laiye to je wi pe, O nrin lo sugbon Oku Eeyan ni. Won ti fi Owu Alantakun gba AISIKI, IRE, IGBEGA ATI OGO elomin-in. Haaa!!!! Aiye toto. Aiye Akamara.

Opolopo Omo Ilee-Iwe ni OWU ALANTAKUN ti ta Okun di Laakaye re. 


Haaa! OWU ALANTAKUN ko le di Igi, Sugbon ti won ba fi di Eeyan. Onitohun ko le bo ninu Ide Aiye.


(1) (ITUWO- ATUDE OWU ALANTAKUN TODAJU πŸ’― Guarantee)

Eku Asin gbigbe kan, Oga gbigbe kan, Egbo Tude, Epo-Obo, E lo gbogbo re papo ninu Odo. Ko kuna daadaa. E o wa tun Ise naa lo mo Ose Dudu tabi Ose Agbanyin. E o wa fi Ororo Maalu po Ose naa papo daadaa, E ko Ose naa sinu Ike funfun Olomori. 

E o ma fi Ose naa we Laarolaaro tabi Alale.


(2) (ITUWO- ATUDE OWU ALANTAKUN TODAJU πŸ’― Guarantee)

A o re Eekana owo wa mejo. A ko gbodo re Eekana Atanpako si oo. A o re Eekana Ese mejo, A ko gbodo re Eekana Atanpako si oo. Egbo Tude. A o lo papo mo gbogbo Eekan naa. A o wa gun gbogbo re mo Ose dudu tabi Ose Aganyi, ti yoo kuna daadaa. A o lo fi OSE naa we ni Ago kan Oru. (1am). Pelu Omi to loworo.


Akiyesi Pataki:- Eekan pere la maa fi OSE naa we. Ti a ba ti we Iwe naa tan, a maa lo so Kainkain naa nu ni ooo.


No comments:

Post a Comment

CONNECTION CLIENT SOAP GEE BOY πŸ’―

 CONNECTION CLIENT SOAP GEE BOY πŸ’―  Ewe Omisinmisin ti amo si eso oju Olohungbo Oojo tuntun die,ao fo Odidi eyin Ororo ibile ti o mo dada 1k...