ASIRI BI A SE LE DA OYIN OGIDI MO π―
1. BI A BA TO OYIN OGIDI LA, O MA TETE TAN LENU JU
OYIN SUGA LO.
2. BI A BA DA OYIN OGIDI SINU OMI, O MA LO SI ISALE OMI NI,
KONI LEFO, KOSI NII DA OJU OMI RU GEGE BI EPO PUPA ATI
ORORO.
3. BI A BA TI IGI ISANA BO INU OYIN FEEREFE, TI A BA TUN SA
ISANA BEE, YOO JO INA BO BA JE PE OYIN OGIGI NI, SUGBON
TO BA JE OYIN IREKE TABI OYIN SUGA, KONI JO INA RARA.
4. OORUN ESO IGI LO MAA RUN JADE LATI INU OYIN OGIDI
5. EERA LE PE BO OYIN OGIDI, BAKANNA LO TUN LE PE BO OYIN
IREKE, NITORI IDI EYI, E MA FI ERA SE DIDAMO OYIN.
6. BI A BA DA OYIN KURO NINU IGO KAN SINU IGO KEJI, OYIN
OGIDI KO NI TETE TAN NINU IGO TI A TI DAA KURO.
7. OYIN OGIDI KII TETE BAJE BI OYIN IREKE ATI OYIN SUGA. OYIN
OGIDI LE LO ODUN MEFA TABI JU BEE LO TI KO SI NI BAJE, TI
AWON TO LOKO NINU IGBO KO BA TI KO KOGBOKOGBO PAPO
MO. TI WON KO SI GBEE SI ILEELE
8. BI E BA DA OYIN OGIDI SINU OMI TABI (TEA) NINU IFE TI A MO
SI (CUP) KONII TETE DARAPO A FI TI A BA FI SIBI ROO PAPO.
9. OYIN OGIDI LE DUDU, O LE FUNFUN, O LE PUPA, EYI WA LOWO
OUNJE TI KOKORO OYIN BA JE ATI IRU ADUGBO TO NGBE.
10. BI A BA DA OGIDI OYIN SILE, KO NI SAN KAAKIRI ILE BI EPO
PUPA TABI KEROSINNI.
Proverb 24.13 Psalm 81.16
IKEDE PATAKI
EYI NI LATI SO FUN GBOGBO EYIN TI E BA NI OKE ISORO MIRAN TI A KO LE SO NINU ILE YI KI E PE MI SORI AGO
WHATSAPP NO. https://wa.me/+2349022547429
GBOGBO ASO KO NI A MA NSA NINU OORUN
No comments:
Post a Comment