OGUN ALEKO 💯
OPOLOPO OKUNRIN LO PADANU IYAWO WON SOWO OKUNRIN
MIRAN NITORI AILE SE DEEDE WON.
OHUN META NI OBINRIN NFE LATI ODO OKUNRIN
EKINNI – OWO
EKEJI – OUNJE
EKETA – OKO
TI O BA LOWO SUGBON TI O KO NI OKO, IYAWO RE MAA BA
OKUNRIN TO NI OKO SUGBON TI KONI OWO LOWO LO.
E LO SI KOOTU KOKOKOKO (CUSTOMARY COURT), EMA RIRAN WO,
ORISIRISI EJO OKOMI, KO KII BA MI SUN, OKO MI N FI OORUN JEMI
NIYA, O TI PE OSU MEFA TI OKO MI TI SI ASO MI SOKE GBEYIN.
ONA ABAYO
OGEDE AGBAGBA DUDU, E LO RA OGEDE AGBAGBA DUDU MEFA, E
GE WEWE SINU KEEGI NLA (5LITRES KEG) KAN. E DA OMI SI KO KUN,
TO BA DI OJO KEJI E BERE SI MAAMU OMI INU RE NI KOOPU (CUP)
KAN NI OWURO, KOOPU KAN NI OSAN, KOOPU KAN NI ALE.
TO BA TI PE OJO MEWA TI E TI RE OGEDE SI OMI. E DA OMI OGEDE
YEN NU, KI E SE OMIRAN
No comments:
Post a Comment