OKO TI KO TOBI TABI TI KO GUN TO 💯
OPOLOPO AWON OMOKUNRIN LO N YO MI LENU, TI WON N BE MI
PE KI N SORO RE LORI YOUTUBE. TI MO BA SO ASIRI BANTABANTA YI
LORI ERO AYELUKARA YOUTUBE AWON TI AISAN YI NSE KO NI PEMI
KI WON DUPE LOWO MI.
AIMOYE ASIRI ITOJU AISAN ORISIRISI TI MO SO LORI YOUTUBE AWON
ENIYAN TI AISAN NAA NDA LAAMU TI WON SI RI IWOSAN OFE GBA
LORI YOUTUBE.
ODE, OPONU TI KO NILO OWO NI WON N PEMI. BI WON TI GBON
NILE OKO BEE NI WON SE GBON NI ILE ALE. EYI LO FA TI MO FI PINNU
LATI MAA SE ENU KU DIEDIE.
OKO TI KO BA GUN TO, ITIJU NLA NI FUN IRU OKURIN BEE, AWON
OKUNRIN TI OKO WON BA KERE, KO NI LE BO SOKOTO LOJU AWON
EGBE RE.
BI IRU WON BA FE TO, WON MA N DOJU KO OGIRI NI.
MO RANTI IGBA TA A WA NI KEKERE, TI A BA LO SI ODO TA A BA FE
WE IWE ODO, OMOKUNRIN KAN WA LAARIN WA, OJU MA N TI TO
BA FEE WE. NITORI IDI EYI KO KI N WE PELU WA.
OMOKUNRIN TI MO N SORO RE YI MA NLO WE IWE TIRE LOTO NI.
OPOLOPO OKUNRIN LO PADANU IYAWO OWURO RE NITORI AISAN
OKO TO KERE TI KO SI TUN GUN DAADAA
OKUNRIN TI OKO RE BA GUN DAADA AWON OBINRIN MA N NI IFE
IRU OKUNRIN BEE NITORI WON MA NTE ATEKANLE NINU KINNI ABE
OBINRIN.
ONA ABAYO
ASIRI KAN NI MO TUN FE SO YI O, GBOGBO OKUNRIN TO BA NI
ISORO OKO TO KERE, OKO TI KO GUN TI KO TUN TOBI RARA (OKO
RINYARINYA) BI AWON OBINRIN TI MA NPE IRU OKO BEE.
E LO RA ESO IGI PANDORO, E GE SI WEWE, E SA SINU OORUN KO GBE
DAADA. TO BA TI GBE TAN, E GUN NINU ODO TABI KI E GBE LO SI
ODO AWON ELERO OGI TABI AWON TO MA NLO ELUBO, E JE KI WON
BA YIN LO KOO KUNNA DAADA. TI E BA TI LO KUNNA DAADAA TAN,
TO DI IYEFUN (POWDER) E RA OORI (SHEA BUTTER) E MA BU DIEDIE
PAPO MO OORI.
LILO RE
TI E BA TI PO IYEFUN PANDORO (PANDORO POWDER) MO OORI TAN,
E MA FI WO ORI OKO, E MA FI PA ORI OKO, E O TUN MAA FI WO OKO
SOKE ATI SI ISALE, PELU ASE OLORUN, OKO YEN YOO TOBI, YOO SI
GUN SI.
PANDORO
ENGLISH NAME: AFRICAN SAUSAGE FRUIT
YORUBA NAME: PANDORO
BOTANICAL NAME: KIGELIA AFRICANA
HAUSA NAME: HANT SAR GIIWAA
IGBO NAME: ALA NWANYI NGBOLOGODO ALA
KI OKO LE TOBI DARA DARA
1. Egbo Osunsun,ao jo,ao da sinu epo pupa,ao mafi boli(plantain)sisun toba tobi koje
2. Eso Bomubomu Nla kan,ao lo kuna,ao dasi inu Oyin igan,ao mafi wo oko wa losi waju
No comments:
Post a Comment