ASINA OWO AGBAOJO ASIRIBIBO TODAJU 💯
Ewe Abamoda
Eyo Atare 21
Oti 33
Ao ja ewe Abamoda Oojo to wa ni arin eyo kan,Ao ko eyo Atare 21 si ni arin,ao fi enu yasi nigba 3 meta
Adura Re. aki mo odi ile de afefe,aki mo yara de era,Omode meji ki bawon gun iyan koro,agba meji ki bawon rin gbedeke wo Oja,Owe baba mi kan ni,Owe baba mi kan lailai ko,Owe Olodumare ni,ati erimi ni ati erimi ni,ati ewa mi ni ati ewa mi ni,Oro ti ema fi gbe ire aje Nlanla wa funmi ni ki ema so nipami,ki egbe ire wami ri,ki efi ire wami kan,Omode,agba,Obirin,Okunrin,ki efi ire aje Sanu funmi. ao se Adura owo si daada,ao jee,ao mu Oti 33 le ni ori
Eledua yii oo gbo aduaa wa oo
No comments:
Post a Comment