Thursday, October 5, 2023

HANDKERCHIEF AIYETA TODAMILOJU BIKU 💯

 HANDKERCHIEF AIYETA TODAMILOJU BIKU 💯 

ao wa white handkerchief tuntun kan,obi abata Oloju mefa  kan,odidi atare 2 meji. 

SISE RE. ao bo epo atare 2 mejeji kuro patata,ao ba padi atare meta ninu odidi atare kan,padi atare odidi atare 2 meji yi o je padi mefa  

AKIYESI. akogbodo je ki koro atare kankan yo jabo nibe o,ao wa ko padi atare mefa yi kale leyin na,ao pa obi abata yi si ona mefa,ao wa fi padi atare kanle ori obi alawe kankan yi o je alawe obi kan,padi atare kan ni ona mefa,ao wa bo arawa si ihoho omoluabi,ao kunle,ao ka owo wa mejeji seyin,ao ma fi enu gbe je ni ikankan,bi aba ti nje alawe obi kan ati padi atare kan,be ni ogun yio ma jade lara wa,ao ma fi hankerchief yi nu gbogbo ara wa,ao tun fi enu gbe alawe obi ati padi atare kan je,ao tun fi hankerchief yi nu gbogbo arawa,be ni ao se ti ao fi je mefefa tan,leyin na ao mu oti Schinap le lori,ao tun fi handkerchief yi nu gbogbo ogun ti oba jade lara wa,ao mu hankerchief yi,ao sa sibi ategun ninu yara.

 LILO HANDKERCHIEF YI RE O. bi aba njade lo pelu awon omo ogun wa,ti ojepe gbogbo awon omo ogun wa koni ogun ibon lara,ao mu ako okuta,ao so mo eti white hankerchief yi,ao duro si iwaju,gbogbo awon omo ogun wa yio wa leyin,ao wa ma fi hankerchief yi loke ori wa,gbogbo ibon ti awon ota ba yin koni ran wa koda koni de odo wa kosi ni ba gbogbo awon ti won ba wa leyin wa rara,sungbon eniti oba koja si iwaju wa ni ibon yio ba,gbogbo awon omo ogun ti oba wa leyin wa abo wa ti bo gbogbo won,ibon ota ibon kankan koni ba won koda huhu kan koni hu lara won

No comments:

Post a Comment

CONNECTION CLIENT SOAP GEE BOY 💯

 CONNECTION CLIENT SOAP GEE BOY 💯  Ewe Omisinmisin ti amo si eso oju Olohungbo Oojo tuntun die,ao fo Odidi eyin Ororo ibile ti o mo dada 1k...