Thursday, October 5, 2023

OKIGBE MARAN TODAJU 💯

 OKIGBE MARAN TODAJU 💯 


OKIGBE ADA ATI OBE ODAJU BIKU 

ao wa opolo ijokun ooye nla kan,odidi atare kan,ao ju opolo ijokun yi sinu omi die,ao fi omi yi bo lori ina jina dada ti opolo yi yio fo petepete ti yio ro,ao yo polo yi sinu ape ao fi omi ti afi se opolo yi jina po ogi fun fun leyina,ao wa Jo opolo yi pelu odidi atare kan ao lokuna,ao wa da gbogbo ebu yi sinu ogi funfun yi ao gbe mu lekana patapata asiri daju okigbe ati maran ota ibon ni koda abere koni le wole si wa lara,asile fi die ninu ebu naa singbere yipo ori. 


OKIGBE AKE (AXE)

Opolo Aaye Kan,ao fi sinu isasun,ao wa bu Ewa(Beans)Agolo Kan Le Lori,ao Wa Bu Omi Lelori,ao wa se jina,ti Oba jina,ao gbodo je ju eyo Ewa meta lo,ao da eleyi ti o ku danu.tabi ki elomiran loo.Odaju.


 OKIGBE TODAJU

ao wa awo iki die,omo irula 9 mesan,eyo atare 9 mesan,eso oju Olongbo 9 mesan,ao lo papo ti yio kun na dada,ao fisingbere yipo apa mejeji,walai odami loju gidi nio

OKIGBE

agbarin pelebe kan,ao lasi meji,ao ge obi abata funfun kan si 201,pupa na 201 eyo atare 201,ao ko wo sinu agbarin yen,ao de ao fi owu etudu we gbogbo arare,ao wawe lowu dudu,ao ran ni awo iki,ao mafi sara jade


OKIGO ORI

ewe alupaida 7 meje,eyo atare 7 meje,ao jo papo ao fisingbere meta meta sori kegbe otun ati osi


OKIGBE

opolo kan,ewe alupaida 9 mesan,ewe abamoda 9 mesan,ao jopo ao dasinu aso funfun ao dinikobere ao ran ni ifunpa


 OKIGBE

gbogbo ifun ako alangba,ao jopo mo odidi atre kan ao fisingbere meta meta si egbe wa mejeji


OKIGBE

ori ako alangba kan,ao ki oruka kan bo lenu,eyo atare 7 meje,ao we lowu dudu ati funfun,ao ran ni ifunpa


 AYETA IBON

ideri oti gudar meji,ao ko eyo atare mesan si,eso afola mesan si ao de ao we lowu dudu ati,funfun,ao mafi sara jade


OKIGBE

opolo ijoku kan,ao ko oruka si ninu re,ao lori mon ori akitan di ojo keta pere


AYETA

Eso oju Olongbo 16,eyo atare 16,ao dini aso pupa,ao mafi ara jade


 ISORA NINU EWU KEWU

ewe Amunimuye,ekuro oju ona,ewe inabiri,odidi atare kan,jijopo eko tutu laofifomu

 

 ISORA

Eku eleri kan,odidi atare aja kan,jijopo,ao fisingbere (3,4,4,3) laya leyin


 OGUN IBON

Orogbo kan,ewe alupaida die,odidi atare kan,ewe sawerepepe,ao fi owo wa ja ibepe dudu kekere kan tikogbodo kan Ile,ao jo papo ao fisingbere lati iho orun de isale beni lati eyin orun nan dele


OKIGBE ATI IBON

egungun aja tiwon fi bo Ogun die,egungun elede die,awo iki,odidi atare kan,jijopo,ao fisingbere (3,3,3,3,3,3) lorikiriki arawa


NOTE

opari tiwon basawada koniran wa tabi kiwon da enu ibon kowa ota yen yio ma da sile


ISORA NINU EWU KEWU

ewe Amunimuye,ekuro oju ona,ewe inabiri,odidi atare kan jijopo eko tutu laofifomu

 

ISORA

Eku eleri kan,odidi atare aja kan,jijopo afisingbere (3,4,4,3) laya leyin


OGUN IBON

orogbo kan,alupaida,odidi atare kan,ewe s⁴awerepepe,ao fi owo wa ja ibepe dudu kan tikogbodo kan Ile,ao jo papo ao fi sin gbere lati iho orun de isale beni lati eyin orun nan dele


OKIGBE ATI IBON

egungun aja tiwon fi bo Ogun,egungun elede awo iki,odidi atare kan jijopo ao fisin gbere (3,3,3,3,3,3) lorikiriki arawa


NOTE

opari tiwon basawada koniran wa tabi kiwon da enu ibon kowa ota yen yio ma da sile

 

IDA ASASI PADA 

Ori ejo oka kan,ori ejo soro kan,fodidi atare kan jijopo gbere (9) fun okunrin gbere (7) fun obinrin lori lamasinsi sugbon ori odo lamatijokosin opo eniyan ni olelo ogun yi 


 AJESARA FUN IBON

Omunu ewe ajeobale 9 mesan,eyo atare 9 mesan,eso werejenje 9 mesan lilopo afisingbere Ejiogbe lapa wa mejeji 


 AGBELEPOTA

Koriko towu lori sare tuntun pelu iyere lilopo afise eja aro gbigbe lamafiseje lepo ni iro sugbon isasun tuntun lamafise leyin ti abaje aseje nan tan isasun yen ao lo bo mon ile ni akogbodo lo isasun yen mon 


 OWO

Ao wa akisa ori akitan eyo mesan lilopo ao dini ikobere owu dudu ati funfun ao maju sapo kiri 


 OKIGBE

Agbarin pelebe,ao lasi meji eyo atare (19) werejenje (19) ao kosinu agbarin yen ao we lowu dudu ati funfun ao ran lawo iki ao ma min si etiwa mejeji laro laro 


ISORA NINU EWUKEWU

Ewe alupaida koni iye apadi tobadoju bo iganan eyo atare mesan ao di ikobere si iyekiye,ao maju sapo kiri

No comments:

Post a Comment

CONNECTION CLIENT SOAP GEE BOY 💯

 CONNECTION CLIENT SOAP GEE BOY 💯  Ewe Omisinmisin ti amo si eso oju Olohungbo Oojo tuntun die,ao fo Odidi eyin Ororo ibile ti o mo dada 1k...