Thursday, October 5, 2023

OGUN IWOSAN ARUN KARUN TODAJU 💯

 OGUN IWOSAN ARUN KARUN TODAJU 💯 

Ewe kan nbe ni ile yoruba oruko re nje (EYINOLOBE)ti awon Alawo funfun npe ni (PHYLLANTUS)AMARUS,ewe yii wulo pupo,arun ara ti o nwosan je igba o le eyokan ti o nje 201,ninu ara,ewe yii kawo awon aisan won yii 

1. Diabates 

2. hypertention 

3. stroke 

4. hppendix 

5. Hannier 

6. staphcoluses 

7. Toilet infection 

8. All the infection in the body such as pile, Idi yiyo etc 

9. Atosin olojo pipe etc ao waa ewe yii ti yio po daadaa, ao fi omi se kofi jina daadaa, ao maa mun, 

 FUN DIABATES

ao maa mun ni emerin lojumo,Aro ki ato jeun,osan ni dede ago meji Tobadi ago meta Abo ao tun mun Tobadi Ago marun gerege ao tun mun Ti aba fe sun lale ao mun ilaji cup ni ao maa mun 

FUN HYPERTENTION

Ao maa mun lemeta lojojumo

FUN STROKE

Ao maa mun bi eni mun omi, ao maa fi se omi mumun

FUN APPENDIX

Ao maa mun lemeji lojojumo 

FUN ANY INFECTION

Ao maa mun lekan lojumo pelu ase Olohun ao maa ri itusile ni kiakia lori gbogbo arun eyikeyi lara  


No comments:

Post a Comment

CONNECTION CLIENT SOAP GEE BOY 💯

 CONNECTION CLIENT SOAP GEE BOY 💯  Ewe Omisinmisin ti amo si eso oju Olohungbo Oojo tuntun die,ao fo Odidi eyin Ororo ibile ti o mo dada 1k...