Friday, October 6, 2023

AWENU ATI EYONU ASINA ERUPE OSAN ATI ORU 💯

 AWENU ATI EYONU ASINA ERUPE OSAN ATI ORU 💯

Fun eni ti ko ri se tabi ti ona dimo
ao bu Erupe die ni iwaju ita ile ti ngbe ni 1:00 ago kan oru,ao tun bu ni 1:00 Osan,ao gun erupe mejeji po mo Ose ti oba wu wa,ao mawa lararo pelu omi tutu
Adura Re. Ori Oru ki buru titi ki opade Osan,Ori Osan ki buru titi ki opade Oru Emi L.Omo L. Gbogbo idamu aye mi ao ni pade mo mobo danu,ninu ilu ti mo wa yi ki ni Owo,ninu adugbo ti mo wa yi ki ni Ola,Nitori wipe iwo ni Olorun Oba ti o gbe Josefu ga ni ile ajoji,wa gbe mi ga

No comments:

Post a Comment

CONNECTION CLIENT SOAP GEE BOY 💯

 CONNECTION CLIENT SOAP GEE BOY 💯  Ewe Omisinmisin ti amo si eso oju Olohungbo Oojo tuntun die,ao fo Odidi eyin Ororo ibile ti o mo dada 1k...