Friday, October 6, 2023

AYAJO OWO RESPECT 💯

 AYAJO OWO RESPECT 💯 

Ao ma je eyo Atare 9,mesan lenu

Gbolohun Re: Aki fi Oro Ogun lo atare 3x eni ba fi Oro ogun lo atare abi Oluwa re wo,Aki fi Oro awe lo Orogbo 3x eni ba fi Oro awe lo Orogbo abi Oluwa re lere wo,Aki fi Oro Ana lo Oku 3x eni ba fi Oro Ana lo Oku,Oku yi o ran Oluwa re lo si Orun Osan gan gan,ni ibi ti mohun lo yi eni ba ni ko si iru mi nibe ki ile lanu ki o gbe mi ki Oku ki o ba ja,ki afefe ba ja,ki omi ba ja.

Akiyesi Pataki: ti a ba fe lo si ibi kan ti eni kan ba fe da oju tiwa tabi ti awa ni ibi kan ti eni kan ba fe da oju ti wa tabi tabukuwa ni a ma lo iru Ise yi o,ti a ba wa lo iru ise yi ti aba kuro nibi dan dan ni ki o si se ti a ba ri wipe won pe wa pe ninu awon ti o wa nibi wa ninu arisan

Ero~Re ni yi: atun je eyo atare mejee lenu ao tu si Owo wa ao fi pa ori wa ki ato lo sibe lati se adura fun eni na ki to le wo san ti ako ba se be arisan yi o gbe eni na de oo

No comments:

Post a Comment

CONNECTION CLIENT SOAP GEE BOY 💯

 CONNECTION CLIENT SOAP GEE BOY 💯  Ewe Omisinmisin ti amo si eso oju Olohungbo Oojo tuntun die,ao fo Odidi eyin Ororo ibile ti o mo dada 1k...